Èdè Gíríìkì jẹ́ èdè àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Gíríìsì àti Kipru.
Álífábẹ́ẹ̀tì wọn jáde láti inú Phoenician script tí ó wá padà di ìkọsílẹ̀ fún èdè Látìn, Cyrillic, Armenian, Coptic, Gothic, àti àwọn ìkọsílẹ̀ mìíràn. Láti nǹkan bíi ẹgbẹ̀rún ọdún mẹ́ta sẹ́yìn ni wọ́n ti ń sọ èdè Gíríìkì ní Balkan peninsula, Ẹ̀rí àkọ́kọ́ tí wọ́n ṣe àkọsílẹ̀ rẹ̀ ni Linear B clay tablet tí wọ́n rí ní Messenia tí ọdún rẹ̀ jẹ́ nǹkan bíi 1450 àti 1350 BC, èyí sì ni ó jẹ́ kí èdè Gíríìkì jẹ́ ọ̀kan lára àwọn èdè tí ó ní àkọsílẹ̀ tó pẹ́ jùlọ.
Greek Gíríkì | |
---|---|
Ελληνικά Ellīniká | |
Ìpè | [e̞liniˈka] |
Sísọ ní | Greece, Cyprus, Greek diaspora. |
Agbègbè | Balkans |
Ìye àwọn afisọ̀rọ̀ | c. 15 million |
Èdè ìbátan | Indo-European
|
Lílò bíi oníbiṣẹ́ | |
Àkóso lọ́wọ́ | Kòsí àkóso oníbiṣẹ́ |
Àwọn àmìọ̀rọ̀ èdè | |
ISO 639-1 | el |
ISO 639-2 | gre (B) ell (T) |
ISO 639-3 | variously: grc – Ancient Greek ell – Modern Greek pnt – Pontic Greek gmy – Mycenaean Greek gkm – Medieval Greek cpg – Cappadocian Greek tsd – Tsakonian Greek |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Èdè Gríkì, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.