Guinea (pípè /ˈɡɪni/, lonibise bi Orile-ede Olominira ile Guinea Faransé: République de Guinée), je orile-ede kan ni Iwoorun Afrika.
Mimo teletele bi Guinea Faranse (Guinée française), nigba miran loni bi Guinea-Conakry lati seyato re si Guinea-Bissau to wa legbe re. Conakry ni oluilu, ibujoko ijoba olomoorile-ede ati ilu ttobijulo.
Republic of Guinea | |
---|---|
Motto: "Travail, Justice, Solidarité" (Faransé) "Work, Justice, Solidarity" | |
Orin ìyìn: Liberté (Faransé) Freedom | |
Ibùdó ilẹ̀ Guinea (dark blue) – ní Africa (light blue & dark grey) | |
Olùìlú àti ìlú tótóbijùlọ | Conakry 9°31′N 13°42′W / 9.517°N 13.700°W |
Àwọn èdè ìṣẹ́ọba | French |
Vernacular languages |
|
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn (2014) |
|
Orúkọ aráàlú | Guinean |
Ìjọba | Unitary presidential republic |
Mamadi Doubouya | |
Bah Oury | |
Aṣòfin | National Assembly |
Independence | |
• from France | 2 October 1958 |
Ìtóbi | |
• Total | 245,857 km2 (94,926 sq mi) (77th) |
• Omi (%) | negligible |
Alábùgbé | |
• Àdàkọ:UN Population estimate | Àdàkọ:UN PopulationÀdàkọ:UN Population (77th) |
• 2014 census | 11,523,261 |
• Ìdìmọ́ra | 40.9/km2 (105.9/sq mi) (164th) |
GDP (PPP) | 2020 estimate |
• Total | $26.451 billion |
• Per capita | $2,390 |
GDP (nominal) | 2020 estimate |
• Total | $9.183 billion |
• Per capita | $818 |
Gini (2012) | 33.7 medium |
HDI (2018) | ▲ 0.466 low · 174th |
Owóníná | Guinean franc (GNF) |
Ibi àkókò | UTCÀdàkọ:Sp (GMT) |
Ojúọ̀nà ọkọ́ | right |
Àmì tẹlifóònù | +224 |
ISO 3166 code | GN |
Internet TLD | .gn |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Guinea, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.