Dubai (Pípè: /duːˈbaɪ/ doo-BYE; Lárúbáwá: دبيّ dubayy) je ikan ninu awon emireti meje to wa ni United Arab Emirates (UAE).
O budo si guusu Ikun-omi Persia lori Arabian Peninsula ohun sini o ni olugbe totobijulo pelu aala ileagbegbe totobijulo larin gbogbo awon emireti leyin Abu Dhabi. Dubai ati Abu Dhabi ni emireti meji pere ti won ni agbara idina lori awon oro pataki ni ileasofin.
Dubai إمارة دبيّ | ||
---|---|---|
Emirate | ||
Emirate of Dubai | ||
| ||
Country | United Arab Emirates | |
Emirate | Dubai | |
Incorporated (town) | 9 June 1833 | |
Founded by | Maktoum bin Bati bin Suhail (1833) | |
Seat | Dubai | |
Subdivisions | Towns and villages Jebel Ali Hatta Al Hunaiwah Al Aweer Al Hajarain Al Lusayli Al Marqab Al Faq Hail Al Sufari Ud al-Bayda Al Malaiha Al Madam Margham Urqub Juwayza Al Qima | |
Government | ||
• Type | Constitutional monarchy | |
• Emir | Mohammed bin Rashid Al Maktoum | |
• Crown Prince | Hamdan bin Mohammed bin Rashid Al Maktoum | |
Area | ||
• Emirate | 4,114 km2 (1,588 sq mi) | |
• Metro | 1,287.4 km2 (497.1 sq mi) | |
Population (2008) | ||
• Emirate | 2,262,000 | |
• Density | 408.18/km2 (97/sq mi) | |
• Metro | 2,262,000 | |
• Nationality (2005) | 26.1% Arab (of whom 17% are Emirati) 42.3% Indian 13.3% Pakistani 7.5% Bangladeshi 2.5% Filipino 1.5% Sri Lankan 0.9% European 0.3% American 5.7% other countries | |
Time zone | UTC+4 (UAE standard time) | |
Website | Dubai Emirate Dubai Municipality |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Dubai, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.