Haile Gebrselassie

Haile Gebrselassie (Àdàkọ:Lang-am, haylē gebre silassē; ojoibi April 18, 1973) je ara Ethiopia asareidaraya ona jijina ati isare ojuona.

O gba eso wura Olympiki meji fun 10,000 metres ati ife-eye Idije Agbaye merin fun ijinna kanna. O bori ni Berlin Marathon lemerin leralera ati Dubai Marathon lemeta leralera. Bakanna, o tun gba ipo kinni ni emerin fun awon idije inuule, ohun si tun ni Adijekinni Marathon Idaji Agbaye 2001. Ni Oṣu kọkanla ọdun 2021, Haile Gebreselassie wa ni iwaju ogun ni Etiopia lodi si awọn ọlọtẹ ti Tigray.

Haile Gebrselassie
Haile Gebrselassie
Gebrselassie at the 2010 Dubai Marathon
Òrọ̀ ẹni
Height1.65 m (5 ft 5 in)
Weight56 kg (123 lb)
Sport
Orílẹ̀-èdèHaile Gebrselassie Ethiopia
RetiredNovember 7, 2010



Itokasi

Tags:

Ethiopia

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Eto eko ni orile-ede NaijiriaÈdè Gẹ̀ẹ́sìSingaporeKòmóròTheatreSọrọ Nipa Awọn igi.bjDavid GrossKíprù3460 AshkovaÀwọn Ẹ̀ka-èdè YorùbáẸkún ÌyàwóTsẹ́kì OlómìniraNamibiaSimple Mail Transfer ProtocolFọ́tòyíyàKọ̀mpútàJẹ́mánìTwitterÌpínlẹ̀ ẸdóTógòHóróThimphu2 AprilIranSomaliaÁsíàÀsìáChinedu IkediezeBeninẸṣinÁrktìkìBùrúndìLinda IkejiÌjọba àìlólóríPalauÌránìIlẹ̀ọbalúayé Rómù Apáìwọ̀orùnHans Georg DehmeltÁfríkàOṣù KẹrinFránsìSeun AjayiAmẹ́ríkàn futbọ́ọ̀lùEre idarayaWilliam Grenville, 1st Baron Grenville21519 JosephhenryGbọ̀ngàn Ìdúnádúrà ÀgbáyéFenesuelaIlé-Ifẹ̀Garba LawalISO 3166CuraçaoOrílẹ̀-èdè PalẹstínìSt. LouisBeirutHawaiiÈdè GríkìISO 639-2ÍndíàKurt Georg KiesingerÌbánisọ̀rọ̀-ọ̀ọ́kánOctavia SpencerÀṣínììsìZanzibarÀwòdì apẹjaÀsìá ilẹ̀ MyanmarÒgún LákáayéEpo🡆 More