Ìṣiṣẹ́àbínimọ́ tabi Gẹ̀nẹ́tíkì (lati Èdè Gíríìkì aye atijo, γενετικός genetikos, γένεσις genesis, “ibere”) gegebi apa eko baoloji, je sayensi awon abimo, ijogun, ati iyasorisi larin awon adiarajo alaaye.
Ìṣiṣẹ́àbínimọ́ da lori idimu ati imuse oniakinkinni awon abinimo, pelu iwa abinimo ninu ahamo tabi adirajo (f.a. ilagbaralori ati isiseabinimoju), pelu ogun latodo obi si omo, ati pelu ipinkari, iyasoto ati iyipada larin awon olugbe. Nitoripe awon abinibi wa ninu gbogbo awon adirajo alaaye, isiseabinibi se lo lati se akomo gbogbo awon sistemu alaaye, latori awon eran ati bakteria, de ori awon ogbin (agaga awon eso oko) ati awon eran osin, de ori awon eniyan (bi ninu isiseabinibi oniwosan).
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Ìṣiṣẹ́àbínimọ́, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.