Napoléon Bonaparte (15 August 1769 – 5 May 1821) jẹ́ olórí ológun àti adarí òṣèlú àti ọmọ bíbí ìlú Corsica ní ilẹ̀ Faranse.
Ó di ìlú-mọ̀ọ́ká ní àsìkò ìyípadà ìṣèjọba ilè Faranse, tí ó sì léwájú àwọn ìjangbara oríṣiríṣi ní àsìkò ogun. Gẹ́gẹ́ bí Napoleon I, òun ni ọba ilẹ̀ Faranse láti ọdún 1804 sí ọdún 1814, àti 1815. Napoleon ṣe àkóso ìjọba ilẹ̀ Yuroopu àti àgbáyé fún bí ọdún mẹ́wá, nígbà tí ó ń léwájú nínú àwọn ogun oríṣiríṣi tí a mọ̀ sí Napoleonic Wars. Ó ja ọ̀pọ̀lọpọ̀ ogun, tí ó sì borí àwọn ogun tí ó sì mu láti gba àwọn ilé lọ́pọ̀lọpọ̀ fún ìjọba Faranse, tí ó sì darí ilẹ̀ Yuroopu lápapọ̀ ṣáájú kí ìjọba rẹ̀ tó ṣubú ní ọdún 1815. Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn adarí ní orílẹ̀ àgbáyé tí wọ́n sì ń kẹ́kọ̀ọ́ nípa ìṣèjọba rẹ̀ jákè-jádò àgbáyé. Ó sì wà nínú àwọn adarí tí ó gbayì jùlọ ní inú ìtàn àgbáyé.
Napoleon Àkọ́kọ́ | |
---|---|
The Emperor Napoleon in His Study at the Tuileries, by Jacques-Louis David, 1812 | |
Emperor of the French | |
Reign | 18 May 1804 – 11 April 1814 20 March 1815 – 22 June 1815 |
Coronation | 2 December 1804 |
Predecessor | French Consulate Himself as First Consul of the French First Republic. Previous ruling monarch was Louis XVI as King of the French (1791-1792) |
Successor | Louis XVIII (de jure in 1814; as legitimate monarch in 1815) Napoleon II (according to his father's will of 1815) |
King of Italy | |
Reign | 17 March 1805 – 11 April 1814 |
Coronation | 26 May 1805 |
Predecessor | Himself as President of the Italian Republic. Previous ruling monarch was Emperor Charles V, crowned in Bologna in 1530 |
Successor | Kingdom disbanded Next monarch crowned in Milan was Emperor Ferdinand I, next king of Italy was Victor Emmanuel II of Savoy |
Spouse | Joséphine de Beauharnais Marie Louise of Austria |
Issue | |
Napoleon II of France | |
Full name | |
Napoleon Bonaparte | |
House | House of Bonaparte |
Father | Carlo Buonaparte |
Mother | Letizia Ramolino |
Burial | Les Invalides, Paris |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Napoleon Bonaparte, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.