Biochemistry, nígbàmíràn wọ́n máa ń pèé ní biological chemistry, jẹ́ ìmọ̀ ìlànà kẹ́míkà àgọ́ ara àtí ìbáṣepọ̀ wọn pẹ̀lú ohun ẹlẹmí.
Nípa ṣíṣe àkóso lílọ-bíbọ̀ iṣẹ́ lágọ́ ara nípasẹ̀ ìtalólobo ìbáṣepọ̀ kẹ́míkà àti lílọ-bíbọ̀ agbára kẹ́míkà làtàrí gbogbo ìbáṣepọ̀ kẹ́míka nínú ara, ìlànà kẹ́míkà nínú ara yìí ní ó máa ń ṣe ìmúgbòòrò bí ara ṣe ń ṣiṣẹ́. Ní bíi ogún ọrundún sẹ́yìn, biochemistry ti ṣe àṣeyọrí lórí bí a ṣe lè ṣàlàyé lórí ìlànà ìgbéayé tí ó ni ṣe pẹ̀lú ìmọ ohun ẹlẹ́mí làti ìmọ̀ ewéko sí ìmọ̀ ìlera, sí ìmọ̀ ìṣiṣẹ́àbínimọ́ ní wọ́n ní ṣe pẹ̀lú ìwádí ìbáṣepọ̀ kẹ́míkà lágọ́ ara. Loní, ìdojúkọ ìwádí ní biochemistry dá lórí òye bí biological molecules ṣe ń f ìlànà tó ń ṣẹlẹ̀ nínú àwọn ètò ẹ̀yà ara.
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Biochemistry, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.