Ṣakí jẹ́ ìlú kan ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́,ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
Ilú Ṣakí ni ó wà ní agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ Agbègbè ìjọba Ìbílẹ̀ Ìwọ̀ Oorun Ṣakí ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́.
Ṣakí Òkè-Ògùn Ṣakí Òkè-Ògùn | |
---|---|
Nickname(s): Ọmọ Ṣakí, Ògún 'ó rọ ikin, alágbẹ̀dẹ 'ò rọ bàtà. Ọmọ Àsabàrí 'ò kọ̀' jà, ọmọ Olóógun 'ò k'eré. Tí ó bá d'ọjọ́ ìjà kíá rán ni sí Àsabàrí, tí ó bá d'ọjọ́ eré kíá rán ni sí Olóógun... | |
Motto(s): Shaki-Ọmọ Àsabàrí, akin l'ójú ogun! | |
Coordinates: 8°40′N 3°24′E / 8.667°N 3.400°E 3°24′E / 8.667°N 3.400°E | |
Country | Nigeria |
OyoState | Oyo State |
Government | |
• Governor | Engr. Oluwaseyi Makinde |
• Okere Of Sakiland | HRM Ọba Khalid Oyeniyi Olabisi |
• Baagi Of Sakiland | High Chief Ghazali Abdulrasheed |
Population (2006) | |
• Total | 388,225 |
• Ethnicities | Yoruba |
• Religions | Muslim 70%& Christians 30% |
Time zone | UTC+1 (WAT) |
• Summer (DST) | UTC+1 (not observed) |
Website | www.oyostate.gov.ng |
Àwọn àpáta ńlá ńlá ni wọ́n yí ìlú Ṣaki ká, Ìlú náà wà ní ẹ̀bá odò Ofiki, odò náà sì já sí Odò Ògùn tàbí Ògùnpa ní ǹkan bí ìwọn ogójì kìlómítà
sí ọgọ́ta kìlómítà sí ẹnu ibodè orílẹ̀-èdè olómìnira Benin . Wón sábà ma ń pe Ṣakí ní ''Ilé àgbọ́n ọ̀gbẹ ouńjẹ ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́'' látàrí iṣẹ́ àgbẹ̀ tí wọ́n yàn láàyò.
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Ṣakí, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.