Senegal

Sẹ̀nẹ̀gàl (Faransé: le Sénégal) tabi Orile-ede Olominira ile Senegal je orile-ede ni Iwoorun Afrika.

Senegal ni Okun Atlantiki ni iwoorun, Mauritania ni ariwa, Mali ni ilaorun, ati Guinea ati Guinea-Bissau ni guusu. Sinu die lo ku ko yipo Gambia ka patapata si ariwa, ilaorun ati guusu, ibi to se ku nikan ni eti okun Atlanti Gambia Ifesi ile Senegal fe to 197,000 km², be si ni o ni onibugbe bi 18 milionu.

Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Sẹ̀nẹ̀gàl
République du Sénégal
Motto: "Un Peuple, Un But, Une Foi"  (French)
"One People, One Goal, One Faith"
Location of Sẹ̀nẹ̀gàl
Olùìlú
àti ìlú tótóbijùlọ
Dakar
Àwọn èdè ìṣẹ́ọbaFrench
Lílò regional languagesWolof, Soninke, Seereer-Siin, Fula, Maninka, Diola,
Orúkọ aráàlúSenegalese
ÌjọbaSemi-presidential republic
• President
Bassirou Diomaye Faye
• Prime Minister
Ousmane Sonko
Independence
• from France
4 April 1960
Ìtóbi
• Total
196,723 km2 (75,955 sq mi) (87th)
• Omi (%)
2.1
Alábùgbé
• 2023 estimate
18,032,473 (61nd)
• Ìdìmọ́ra
92/km2 (238.3/sq mi)
GDP (PPP)2008 estimate
• Total
$21.773 billion
• Per capita
$1,739
GDP (nominal)2008 estimate
• Total
$13.350 billion
• Per capita
$1,066
Gini (1995)41.3
medium
HDI (2007)0.464
Error: Invalid HDI value · 166th
OwónínáCFA franc (XOF)
Ibi àkókòUTC
Ojúọ̀nà ọkọ́right
Àmì tẹlifóònù221
Internet TLD.sn

Dakar ni oluilu re to wa lori Cap-Vert Peninsula ni eti Okun Atlantiki. Bi iye ida kan ninu meta awon ara Senegal ni won n gbe labe ila aini kakiriaye to je US$ 1.25 lojumo.



Itokasi

Tags:

Atlantic OceanGambiaGuineaGuinea-BissauIwoorun AfrikaMaliMauritaniaÈdè Faransé

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Ìṣeọ̀rọ̀àwùjọAmerican footballÈṣùLẹ́tà gbẹ̀fẹ̀OwónínáNọ́mbà àkọ́kọ́Nikita KhrushchevIlé234 BarbaraHTMLGaza Strip201 Penelope17 OctoberArunachal PradeshKòkòròBomadiPópù Gregory 10kIkọ́Olaitan IbrahimAuguste BeernaertMurtala MuhammadNeanderthalBleach (mángà)YorùbáDonald TrumpIlẹ̀ọba Aṣọ̀kanCalabarẸ̀bùn NobelFẹlá KútìỌjọ́ ÀìkúC++Elihu RootPornhubÌgbà Sílúríà12 FebruaryGenevaDysprosiumA tribe called Judah633 ZelimaÌlú BeninOrúkọ YorùbáMariam CoulibalyÒrìṣà AgẹmọHermann HesseIsaac KwalluÌwé àwọn Onídàjọ́Ibadan Peoples Party (IPP)Maria NajjumaMajid Michel13 Octoberqi31gÒṣèlú aṣojúỌjọ́ àwọn Ọmọdé(5813) 1988 VLRadonÌran YorùbáNiger (country)Ọrọ orúkọ🡆 More