Akátá

Akátá (Acinonyx jubatus; /ˈtʃiːtə/) jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ẹbí ológbò tó tóbi jùlọ tí wọ́n sì pọ̀ lórílẹ̀ alààyè.

ológbò Ẹ̀yà ẹranko yí wópọ̀ jùlọ ní agbègbè Sàhárà Àríwá ilẹ̀ Adúláwọ̀,Southern, East Africa, àti àwọn díẹ̀ lára ìletò ní orílẹ̀ -èdè Iran. Ẹranko yí fẹ́ràn láti máa gbé ní àwọn orílẹ̀ gbígba, níbí tí koríko pẹ́ṣẹ́pẹ́ṣẹ́ wà.

Cheetah
Temporal range: Pleistocene–Holocene, 1.9–0 Ma
Akátá
Female cheetah in KwaZulu Natal, South Africa
Acoustic repertoire of cheetahs
Ipò ìdasí
Akátá
Vulnerable  (IUCN 3.1)
Ìṣètò onísáyẹ́nsì
Subspecies
  • Southeast African cheetah (A. j. jubatus) (Schreber, 1775)
  • Asiatic cheetah (A. j. venaticus) (Griffith, 1821)
  • Northeast African cheetah (A. j. soemmeringii) (Fitzinger, 1855)
  • Northwest African cheetah (A. j. hecki) (Hilzheimer, 1913)
Akátá
The range of the cheetah

Àdàkọ:Leftlegend Àdàkọ:Leftlegend Àdàkọ:Leftlegend Àdàkọ:Leftlegend

Synonyms

Ìrísí rẹ̀

Akátá jẹ́ ẹranko tí ó ní àwọ̀ àmúlù-málà oríṣiríṣi bí awọ̀ Yẹ́lò, funfun, tí awọọ̀ dúdú ara rẹ̀ sì tó ẹgbẹ́ẹ̀rún méjì níye. Ẹranko yí kìí fi bẹ̀ẹ́ sanra, orí rẹ̀ kò tàbí ó sì rí roboto. Awọ̀ irun dúdú ni ó pààlà tí ó sì yí ojú rẹ̀ po. Àyà ẹranko yí fẹ̀ ó sì jìn sínú díẹ̀ ní ìwọ̀n 70–90 cm (28–35 in) . Ó ga nílẹ̀, ẹsẹ̀ rẹ̀ sì tíínrín, Bákan náà ni ó ní ìrù aláwọ̀ kànákìní tí ó gùn níwọ̀n ẹsẹ̀ bàtà. Èyí tí ó bá tàbí jùlọ lò ma ń gbésìọ̀n tó 21–72 kg (46–159 lb)

Bí wọ́n ṣe ń ṣọdẹ

Gẹ́gẹ́ bí a ti mọ̀ wípé ẹranko yí ni ó yára , tí ó mọ eré sá ju ohunkóhun lọ ní orí ilẹ̀. Ó lè sá iye kìlómítà Mẹ́rìnlélọ́gọ́ta láàrín wákàtí kan, àyà fún ìdinwọ̀n ọ̀nà jíjìn 64 km/h (40 mph) lásìkò tí ó bá fẹ́ pẹran jẹ,ó sì lè sa ìwọ̀n 112 km/h (70 mph) fún ọ̀nà tí kò jìn 100 m (330 ft). Látàrí ìjáfáfá rẹ̀ yí ni kò fi sí ẹranko tó ṣòro fun láti kọlù láì pa.

Àwọn Ìtọ́kasí

Tags:

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Ezra OlubiIkúAkanlo-edeÌbánisọ̀rọ̀-ọ̀ọ́kánMons pubisLebanonÌṣèlú ilẹ̀ Sẹ̀nẹ̀gàlFísíksì3GP àti 3G2Ìsirò StatistikiSíńtáàsì Yorùbá22 December2024Internet Relay ChatGoogleÒgún LákáayéÌtànÈdè Gẹ̀ẹ́sìOnome ebiÀwọn Ẹ̀ka-èdè YorùbáEuropeRio de JaneiroOṣù Kínní 7IfáOjúewé Àkọ́kọ́Pópù LinusDejumo LewisThe New York TimesIsaiah WashingtonÀsà Ìgbéyàwó ní ilè YorùbáÀsà oge ṣíṣẹ́ ní ilè yorùbáGbólóhùn YorùbáPólándìRọ́síàIni Dima-OkojieIPv6Itan Ijapa ati AjaAustríàVictoria University of ManchesterLítíréṣọ̀Alẹksándrọ̀s Olókìkí23 JuneCaracas(211536) 2003 RR11Ahmed Muhammad MaccidoSalvador AllendeÀwòrán kíkùnInternetBùrúndìKarachiOduduwaOrílẹ̀2009Lẹ́tà gbẹ̀fẹ̀🡆 More