Ẹ̀bùn Ọ́skà

Àwọn Ẹ̀bùn Akádẹ́mì tàbí Ẹ̀bùn Ọ́skà jẹ́ ẹ̀bùn ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ fíìmù tí American Academy of Motion Picture Arts and Sciences ma ń fún olùdarí eré, òṣèrè àtí olùkọ̀tàn fún iṣẹ́ takuntakun ní ilé iṣẹ́ fíìmù.

Ayẹyẹ ẹ̀bùn yìí jẹ́ ìkan lára àwọ́n ayẹyẹ èbùn tó lókìkí jùlọ ní gbogbo àgbáyé. Osì tún jẹ́ Ayẹyẹ ẹ̀bùn tó pẹ́ júlọ tí ó si ma ń dàgbeléwò lórí ẹ̀rọ amóùnmáwòran ní orílẹ̀ èdè tó ju igba lọ. Aẁọn ẹ̀bùn ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ fíìmù bi tiẹ̀ ni Grammy Awards (fún orin), Emmy Awards (fun amóùnmáwòran), àti Tony Awards (fún tíát̀à)

Ẹ̀bùn Ọ́skà
Ẹ̀bùn Ọ́skà
Ère ẹ̀bùn ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ fíìmù Amẹ́ríkà
Bíbún fún fún iṣẹ́ takuntakun ní ilé iṣẹ́ fíìmù Améríkà
Látọwọ́ Academy of Motion Picture Arts and Sciences
Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà
Bíbún láàkọ́kọ́ May 16, 1929
Ibiìtakùn oníbiṣẹ́ Oscars.org

Ìtọ́kasí

Tags:

Grammy Awards

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Paul NewmanÌwé Àṣẹ Aṣàlàyé Ọ̀fẹ́ GNULítíréṣọ̀MassachusettsLagos StateÀṣàHerbert MacaulayÀṣà Ìsọmọ-lórúkọ nílẹ̀ YorùbáAustrálíàVictoria University of ManchesterÀrún èrànkòrónà ọdún 2019Léon BlumISO 8601King's CollegeLinda IkejiBama, NàìjíríàLionel BarrymoreSanusi Lamido SanusiÌṣiṣẹ́àbínimọ́2009.aqGoogleNecmettin ErbakanGúúsù Amẹ́ríkàInáAyéFrançois FillonSQL4 June.cdSaadatu Hassan Liman29 AprilMilli TarānaOsita IhemeH.264/MPEG-4 AVCKárbọ̀nùDaniel NathanielFenesuelaIléOwe YorubaNàìjíríàDavid BeckhamMicrosoft WindowsAbidjanOgun Àgbáyé KìíníOwo siseYorùbáNigerian People's PartySARS-CoV-2ISO 3166-1Odunlade AdekolaLinda EjioforỌkọ̀-àlọbọ̀ Òfurufú7 AprilTheodor HeussPópù Felix 3kAloma Mariam MukhtarISO 3166-2Nkiru OkosiemeDynamic Host Configuration ProtocolBẹ̀lárùsJuliu KésárìRonald ReaganNọ́rwèyHilary SwankAdrien Brody🡆 More