Jésù

Jésù ará Násárẹ́tì (c.

5 BC/BCE – c. 30 AD/CE), tàbí Jésù Kírísítì tabi Jésù, jẹ́ ẹni tó ṣe kókó jùlọ, yàtọ̀ sí Ọlọ́run nínú Ẹ̀sìn Kírísítì, tí àwọn ẹlẹ́sìn náà gbà gẹ́gẹ́ bí Olùgbàlà Aráyé, èyí tí ó jẹ́ àsọtẹ́lẹ̀ ni Májẹ̀mú Láéláé nínú Bíbélì, tí gbogbo àwọn ẹlẹ́ṣin Kíristi tàbí irú wọn gbà pé òun ni Ọmọ Ọlọ́run àti àwòrán Ọlọ́run tí ó jí dìde nínú ipò òkú. Islamu gba Jesu gege bi woli ati Messiah. Ọ̀pọ̀ àwọn ẹ̀sìn mìíràn ni wọ́n tún tẹrí ba fún un lóríṣi ọ̀nà. Jésù jẹ́ ẹnìkan tó ṣe pàtàkì nínú ìtàn ọmọ ènìyàn.

Jésù ará Násárẹ́tì
Half-length portrait of younger man with shoulder-length hair and beard, with right hand raised over what appears to be a red flame. The upper background is gold. Around his head is a golden halo containing an equal-armed cross with three arms visible; the arms are decorated with ovals and squares.
6th-century mosaic of Jesus at Basilica of Sant'Apollinare Nuovo in Ravenna. Though depictions of Jesus are culturally important, no undisputed record of what Jesus looked like is known to exist.
Ọjọ́ìbíc. 4 BC/BCE
Bethlehem, Judea, Ilẹ̀ọbalúayé Rómù (traditional); Nazareth, Galilee (historical Jesus)
Aláìsíc. 30 AD/CE
Calvary, Judea, Ilẹ̀ọbalúayé Rómù (According to the New Testament, he rose on the third day after his death.)
Cause of deathCrucifixion (Historically trusted, important meaning in Christian belief)
No cause/death disputed (Islamic belief)
Resting placeTraditionally and temporarily, a garden tomb located in what is now the Church of the Holy Sepulchre, Jerúsálẹ́mù.



Ẹ tún le ka

Àwọn Ìtọ́kasí

Tags:

ChristianityIslamOld Testament

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

George ReadOjúewé Àkọ́kọ́Abraham LincolnJBIGỌdún EgúngúnNobel Prize1972 Yi XingJennie KimKenneth ArrowHamburgEuroKàsínòJulian SchwingerSesi Oluwaseun WhinganYukréìnIṣẹ́ Àgbẹ̀Ọrọ orúkọỌbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀Ísráẹ́lìISO 4217MársìIṣẹ́ ọnàẸgbẹ́ kọ́múnístìJẹ́mánìFrancisco Franco23 AprilLáọ̀sJapanB.L. AfakiryeItan Ijapa ati AjaEarthVladimir PutinÀjákálẹ̀ àrùn káàkiriayé èrànkòrónà ọdún 2019 2020Orin fújìRihannaMemphisParisiVieno Johannes Sukselainen8 SeptemberKọ̀mpútàZulu.alLagos StateFrederick North, Lord NorthIsaac KwalluPaul NewmanErin-Ijesha WaterfallsFestus KeyamoÌmọ̀ Ẹ̀rọÈdè EsperantoLere PaimoFàdákàolómiKòlómbìàÀṢÀ ÌKÍNI NÍ ÀWÙJỌ YORÙBÁ.gaSQLFirginiaÈdè HébérùLẹ́tà gbẹ̀fẹ̀SaxonyBórọ̀nùỌdẹ🡆 More