Erin (tàbí àjànàkú) jẹ́ ẹranko afọ́mọlọ́mú orí ilẹ̀ títóbi tí a kà sí ìbátan méjì ti ẹbí Elephantidae (Ẹ̀dá-àjànàkú): Elephas àti Loxodonta.
Irú erin mẹ́ta ló yè lóde òní: àjànàkú ọlọ́dàn Áfíríkà, àjànàkú onígbó Áfíríkà, àti àjànàkú Ásíà (tí a tún pè ní àjànàkú Íńdíà). Gbogbo irú erin yòókù ti kú run, àwọn kan kú run ní sànmánì olómidídì, ṣùgbọ́n, ó ṣeé ṣe pé àwọn aràrá erin abirun-lára kan yè títí dé nǹkan bíi 2,000 BCE.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Erin, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.