Alice Ann Munro (oruko baba Laidlaw; ojoibi 10 July 1931) je olukowe ara Kanada to unkowe ni ede Geesi.
O gba Ebun Nobel ninu Litireso fun odun 2013 ati Man Booker International Prize 2009 fun gbogbo ise owo re, bakanna o gba Governor General's Award Kanada ni emeta fun iwe itan akodun re.
Alice Munro | |
---|---|
Ọjọ́ ìbí | Alice Ann Laidlaw 10 Oṣù Keje 1931 Wingham, Ontario, Canada |
Èdè | English |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Canadian |
Genre | Short stories |
Notable awards | Governor General's Award (1968, 1978, 1986) Giller Prize (1998, 2004) Man Booker International Prize (2009) Nobel Prize in Literature (2013) |
Spouse | James Munro (1951–1972) Gerald Fremlin (1976–2013) |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Alice Munro, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.