Ọba

Ọba jẹ́ ọkùnrin tí ó ń ṣolórí Ìlú ilẹ̀ tàbí orílẹ̀-èdè nítorí wípé ó lẹ́tọ̀ọ́ láti wà nípa adarí.

O le je taara lati inu ebi re tabi nitoripe ebi re lokan. Opo awon ni ile Yoruba lori bayi. Won ni awon afọbajẹ ti won gbimo ibo ni tabi inu ebi wo ni oba to kan yio ti wa. Ni Europe oba n je lati inu ebi kanna. Yio gori ite taara lati odo bàbá tabi ìyá re.

Ọba
Ọba Ataọ̀jà ilẹ̀ Yorùbá

Iyawo oba ni a n pe ni ayaba tabi ayaoba. Ni Europe obìnrin yi le gun ori ite ti oba ba ku, eyi ko je be ni ile Yoruba nibi ti obinrin ko le di oba.

Ti olori orile-ede kan ba je oba a n pe iru ijoba yi ni idobaje, ti oba na si n je adobaje.


Itokasi

Tags:

BàbáEuropeYorubaÌlúÌyáỌkùnrin

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

(6065) 1987 OCSalvatore QuasimodoSàmóà Amẹ́ríkàSámi soga lávllaTógòÌṣeọ̀rọ̀àwùjọSingapore22 DecemberGeorge Clinton (Igbákejì Ààrẹ)3 NovemberPsamtik 1kISO 639-3.nlSenior Advocate of NigeriaOṣù Kẹ̀sánMóldófàOwe YorubaÀwọn Ìdíje Òlímpíkì Ìgbà Oru 2004Kalẹdóníà Tuntun7 NovemberOmoni OboliArkansasISO 3166-3Diamond JacksonConstantine IKúbàHypertextAdunni AdeGíríìsì234 BarbaraÀlọ́Ìsọ̀kan Sófìẹ̀tì3 MayAustrálíàVyborgOffice Open XMLNebkaure AkhtoyẸ̀bùn NobelMọfọ́lọ́jì èdè YorùbáAyo AdesanyaOlódùmarèBenjamin MkapaTEmperor MeijiSwítsàlandìMary AkorBernard Bosanquet (amòye)GoogleAntárktìkìUlf von EulerManifẹ́stò KómúnístìEyínMiguel MiramónAzareỌ̀rọ̀-Orúkọ (Èdè Yorùbá)Ìjàmbá ìtúká ẹ̀búté Bèírùtù ọdún 202013 October28 SeptemberRita DominicÌjímèrèBhumibol Adulyadej21 JuneYorùbáLuis Carrero BlancoDelawareÌwé àwọn Onídàjọ́Turkey🡆 More