Ìṣírò

Isiro

Ìṣírò
Tábìlì ìsirò

Awoyemi, Jolaoluwa

AWÓYẸMÍ JỌLÁOLÚWA

ÌṢIRÒ

Àwọn Yorùbá ní ọ̀nà tí wọn ń gbà ṣe ìsirọ̀, bẹ́ẹ̀ ní àti ọmọkékeré ní àwọn Yorùbá ti ń kọ́ ọmọ wọn ni ìṣirò ní ṣíṣe. Wọn yóò ni kí ó máa fi ení, èjì kọrin, ṣere bíi

Ení bí ení ni ọmọde ńkawó

Èjì bí èjì ni àgbàlà ń tayò

Ẹ̀ta bi ẹta ẹ jẹ́ ka tárawa lọ́rẹ

Ayò tí ta náà tún jẹ́ ọ̀nà tí àwọn Yorùbá fi máa ń kọ ìṣirò Yorùbá ni àwọn ọ̀nà tí wọ́n fi ń ṣe ìsirò wọn fún àpẹẹrẹ “lé”, “dín”, “àádọ́”, “ẹ̀ẹ́dẹ́”, - jẹ́ àwọn ọ̀nà fún ìfilé àti ìyokúrò ìṣirò wọn.

Apẹẹrẹ ìṣirò Yorùbá

1-óókan

10-ẹ̀wá

20-ogún

21-Ọ̀kàn lè lógún (20+1 = ọ̀kan lé ni ogún)

26-ẹ̀rìndínlọ́gbọ̀n (30-4 = Ọgbọ̀n dín mẹ́rin)

30-Ọgbọ̀n

40-Ogójì (20x2 = Ogún méjì)

60-Ọgọ́ta (20x3 ogún mẹ́ta)

100-Ọgọ́rùn-ún (20x5) = Ogún lọ́nà márùn-ún)

120-Ọgọ́fà (20x6 = Ogún lọ́nà mẹ́fà)

50-àádọ́ta (20 x3 = 10, ẹ́wàá dín nínú ogún mẹ́ta)

200-Igba

240-Òjìlélúgba (40+200; Òjì = 40)

300-Ọ̀ọ́dúnrún

340-Ọ̀tàdín nírinwó (400-60 = ọ̀tà = 60 lọ́gbọ́ta)

800-Ẹgbẹ̀rin (igba mẹrin 200x4)

900-Ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀rún (1000-100 = Ọgọ́rùn-ún dín ni Ẹgbẹ̀rún

1000-Ẹgbẹ̀rún

1600-Ẹgbẹ̀jọ (200x8 = igba méjọ

2000-Ẹgbẹ̀wàa (ẹgbàá) (200x10 – igba ní ọ̀nà mẹ́wàá)

4000-Ẹgbàajì (2000x2)

6000-Ẹgbàata (2000x3)

7000-Ẹ̀ẹ́dẹ́gbàárin (8000-100 = Ọgọ́rùn-ún, dín nínú Ẹgbàárin (800)

10, 000 -Ẹgbàarùn-ún (Ẹgbẹ̀rùn-ún àádọ́ta ẹgbẹ̀rùn-ún - àádọ́ta ọ̀kẹ́).



Itokasi

Tags:

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

FirginiaṢàngóOkpokoFúnmiláyọ̀ Ransome-KútìFaithia BalogunÈdè TúrkìISO 31-10Ilé-Ifẹ̀Guinea-BissauGoogleEré ÒṣùpáBoris YeltsinRonald Colman.cmAloma Mariam MukhtarDélé Mọ́mọ́dùItan Ijapa ati AjaHamburgFránsìBeirutÀjákálẹ̀ àrùn káàkiriayé èrànkòrónà ọdún 2019 2020Àwọn Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ NàìjíríàSaint HelenaDaniel NathanielSístẹ́mù ajọfọ̀nàkò jẹ́ọ́gráfìÁljẹ́brà onígbọrọ7 AprilÀríwáIlẹ̀ọbalúayé Rómù ApáìlàoòrùnÀṣà Ìsọmọ-lórúkọ nílẹ̀ YorùbáHassiomuPhoebe EbimiekumoTheodor HeussMariam Alhassan AloloMọ́skòAbraham LincolnỌdẹÀwọn Ìdíje ÒlímpíkìBill Clinton4363 Sergej(9989) 1997 SG16.guAfeez OwóCETEP City UniversityÒrìṣà EgúngúnÍsótòpùGlobal Positioning SystemBórọ̀nùÀkójọ àwọn ìpínlẹ̀ Nàìjíríà bíi ìpọ̀síènìyànISO 128OSI modelSílíkọ́nù22 MarchOlusegun Olutoyin AgangaẸ̀tọ́-àwòkọ.tc.biRenée ZellwegerHenri BecquerelRichard NixonLa RéunionHypertextÌránìVictoria University of Manchester🡆 More