Boolu-Afesegba

Bọ́ọ̀lù-àfẹsègbá jẹ́ ọ̀kan lára àwọn eré-ìdárayá tó ní ṣe pèlú fífi ẹsẹ̀ gbá bọ́ọ̀lù.

Eré-ìdáraya h yìí pẹ̀ka sóríṣiríṣi ọ̀nà, ara rẹ̀ la ti rí association football, gridiron football tàbí American football tàbí Canadian football, Australian rules football, rugby union pẹ̀lú rugby league àti Gaelic football. Oríṣi ẹ̀ka bọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá wọ̀nyí ní nǹkan tó pa wọ́n pọ̀, tí a mọ̀ sí kóòdù bọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá

Boolu-afesegba
Boolu-Afesegba
An attacking player (No. 10) attempts to kick the ball past the goalkeeper and between the goalposts to score a goal
Highest governing bodyFIFA
Nickname(s)Football, soccer, futbol, footy/footie, "the beautiful game"
First playedMid-19th century England
Characteristics
ContactYes
Team members11 per side
Mixed genderYes, separate competitions
CategorizationTeam sport, ball sport
EquipmentFootball
VenueFootball pitch
Olympic1900
Boolu-Afesegba
Boolu-Afesegba
Boolu-Afesegba
Boolu-Afesegba
Boolu-Afesegba
Boolu-Afesegba
Several codes of football. Clockwise from top left: association, gridiron, rugby union, Gaelic, rugby league, and Australian rules

Oríṣiríṣi ìtọ́kasí ló wà fún bọ́ọ̀lù ìbílẹ̀ tí wọ́n ń gbá káàkiri àgbááyé. Ó sì ní òfin tó de wọ̀n, àwọn òfin yìí ti wà láti sẹ́ńtúrì kọkàndínlógún. Ìtànkálẹ̀ British Empire mú kí àwọn òfin yìí tàn káàkiri eré náà.

Ní ọdún 1888, wọ́n ṣe ìdásílẹ̀ The Football League ní England, èyí sì jẹ́ ẹgbẹ́ bọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá alámọ̀dájú àkọ́kọ́. Ní sẹ́ńtúrì ogún, ọ̀pọ̀lọpọ̀ bọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá lọ́ríṣiríṣi wá di ìlú-mọ̀ọ̀nká, tí wọ́n sì ń gbá káàkiri orílẹ̀-èdè ní àgbááyé.


Àwọn ìtọ́kasí

Tags:

American footballAssociation football

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

2024Jẹ́mánìIsaiah WashingtonWiki CommonsAustrálíàLọndọnuSARS-CoV-2Maseru1117 ReginitaFilipínìỌ̀rànmíyànAdaptive Multi-Rate WidebandÌwéOctave MirbeauỌ̀rọ̀-Orúkọ (Èdè Yorùbá)Ìṣèlú ilẹ̀ Sẹ̀nẹ̀gàlWalter MatthauNigerian People's PartyÀmìọ̀rọ̀ QRMediaWikiỌbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀OmiSheik Muyideen Àjàní Bello1151 IthakaR. KellyÒgún LákáayéTeni (olórin)Ẹ̀bùn Nobel nínú Lítíréṣọ̀AustríàItan Ijapa ati AjaPornhubAbubakar MohammedÀgbérò PythagorasÀsà oge ṣíṣẹ́ ní ilè yorùbá28 JuneIkúOpeyemi AyeolaXBobriskyPópù Gregory 16kBarbara SokyChris BrownInternet Relay ChatÒndó TownFile Transfer ProtocolMegawati SukarnoputriSíńtáàsì YorùbáMons pubisAderemi AdesojiC++SeattleÌpínlẹ̀ ÈkìtìÌpínlẹ̀ ÒgùnEl SalfadorÀjẹsára Bacillus Calmette–GuérinỌjọ́ RúWeb browser🡆 More