Síríà (/ˈsɪriə/ ( listen) SI-ree-ə; Lárúbáwá: سورية Sūriyya or سوريا Sūryā; Àdàkọ:Lang-syr; Àdàkọ:Lang-ku), lonibise bi Orileominira Arabu Siria (Lárúbáwá: الجمهورية العربية السورية Al-Jumhūriyyah al-ʿArabiyyah as-Sūriyyah Arabic pronunciation (ìrànwọ́·ìkéde)), jẹ́ orílẹ̀-èdè ní Apá ìwòorùn Asia, ó ní ibodè pẹlú Lebanon àti Omi-òkun Mediteraneani ní ìwọ̀oọ̀rùn, Turkey ní àríwá, Iraq ní ìlàoòrùn, Jordan ní gúúsù, àti Israel ní gúúsù-ìwọ̀oòrùn.
Syrian Arab Republic الجمهورية العربية السورية Al-Jumhūriyyah al-ʿArabiyyah as-Sūriyyah | |
---|---|
Orin ìyìn: Homat el Diyar Guardians of the Land | |
Olùìlú | Damascus |
Ìlú tótóbijùlọ | Aleppo |
Àwọn èdè ìṣẹ́ọba | Arabic1 |
Orúkọ aráàlú | Syrian |
Ìjọba | Secular single-party state |
• Ààrẹ | Bashar al-Assad |
• Alákóso Àgbà | Riyad Farid Hijab |
Independence | |
• From France | 17 April 1946 |
Ìtóbi | |
• Total | 185,180 km2 (71,500 sq mi) (88th) |
• Omi (%) | 1.1 |
Alábùgbé | |
• 2011 estimate | 22,457,763 (53rd) |
• Ìdìmọ́ra | 118.3/km2 (306.4/sq mi) (101st) |
GDP (PPP) | 2011 estimate |
• Total | $105.238 billion |
• Per capita | $5,043 |
GDP (nominal) | 2010 estimate |
• Total | $60.210 billion |
• Per capita | $2,958 |
HDI (2010) | ▲ 0.712 Error: Invalid HDI value |
Owóníná | Syrian pound (SYP) |
Ibi àkókò | UTC+2 (EET) |
• Ìgbà oru (DST) | UTC+3 (EEST) |
Ojúọ̀nà ọkọ́ | right |
Àmì tẹlifóònù | 9632 |
Internet TLD | .sy, سوريا. |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Síríà, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.