Ede Sindhi (Sindhi: سنڌي, Urdu: سندھی,Devanagari script: सिन्धी, Sindhī) je ede ni agbegbe Sindh ni Pakistan loni.
Iye awon eniyan to un so ni Pakistan je 24,410,910, bakanna ni India iye awon to n so je 2,535,485. O je ede iketa ni Pakistan, ati ede ibise ni Sindh ni Pakistan. O tun je ede ibise ni India. Kadi idanimo ti ijoba ile Pakistan un te jade je ni ede meji nikan pere, Sindhi ati Urdu.
Sindhi | ||||||
---|---|---|---|---|---|---|
سنڌي , सिन्धी ,Sindhī | ||||||
Sísọ ní | Pakistan, India. Also Hong Kong, Oman, Philippines, Singapore, UAE, UK, USA, Afghanistan | |||||
Agbègbè | South Asia | |||||
Ìye àwọn afisọ̀rọ̀ | 21 million | |||||
Èdè ìbátan | Indo-European
| |||||
Sístẹ́mù ìkọ | Arabic, Devanagari, Laṇḍā | |||||
Lílò bíi oníbiṣẹ́ | ||||||
Èdè oníbiṣẹ́ ní | Sindh, Pakistan India | |||||
Àkóso lọ́wọ́ | Sindhi Language Authority (Pakistan) | |||||
Àwọn àmìọ̀rọ̀ èdè | ||||||
ISO 639-1 | sd | |||||
ISO 639-2 | snd | |||||
ISO 639-3 | snd | |||||
|
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Èdè Sindhi, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.