Ìlú ńlá kan nìyí ní ìlà-oòrùn àríwá ilẹ̀ Scotland.
Ara Káúntì (County) Aberdeenshire ni ó wà tẹ́lẹ̀. Láti oṣù kárùn-ún ọdún 1975 ni ó ti di ara Grampian. Wọ́n máa ń pe Aberdeen ní ‘granite city’. Ó ní Yunifásítì kan tí wọ́n dá sílẹ̀ ní 1494. Aberdeen Angus ni wọn máa ń pe orúkọ àgùntàn kan tí ó gbajúmọ̀ ní Aberdeen. Àwọn ará ìlú Aberdeen ni wọ́n ń pè ní Aberdonian.
Aberdeen Aiberdeen Obar Dheathain | |
---|---|
Marischal College from Broadhill | |
Nickname(s): Granite City, Oil Capital of Europe, Silver City | |
Population | |
• Total | Urban area - 184,788 (2,001 census) |
• Density | 1,089/km2 (2,819/sq mi) |
Website | aberdeencity.gov.uk |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Aberdeen, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.