Mọ́skò

Mọsko ni olú-ìlú Rọ́síà.

Ìlú nlá ni. Orí odò Moskva ni ó wà. Odún 1918 ni ó di olú-ìlú USSR nígbà tí wón gbé olú-ìlú yìí kúrò ní Leningrad. Moscow ni ìlú tí ó tóbi jù ní Rósíà. Oun ni ó wà ní ipò kefà tí a bá ní kí á ka àwon ìlú tí ó tóbi ní ilé-ayé. Ìlú tí ó léwà ni Moscow. Uspenki Cathedral tí ó wà ní ibè ni wón ti máa n dé àwon tsar (àwon olùdarí Rósíà) lade láyé àtijó. Ibè náà ni Arkhangelski tí wón ti n sin wón wà. Ilé-isé àti Ilé-èko pò ní ibè Lára àwon ilé-èkó ibè ni. Lomonosov University tí ó jé University ìjoba wa ni ibe. Orí òkè Lenin ni wón kó o sí òun sì ni University tí ó tóbi jù ní Rósíà. Ibè náà ni USSR Academy of Sciences wa. Mùsíómù, ilé-ìkàwé àti tíátà wà níbè. Àwon Bolshoi Theatre and Ballet, the State Symphony Ochestra àti the State Folk Dance Company tí ó wà ni Moscow gbayì gan-an ni.

Mọsko
Red Square
Red Square
Area
 • Total1,081 km2 (417 sq mi)
Population
 • Total12,382,754





Itokasi

Tags:

Rọ́síà

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

.egÀṣàMayotteÌnáwóÀdírẹ́ẹ̀sì IPÍslándìỌrọ orúkọÌjàmbá ìtúká ẹ̀búté Bèírùtù ọdún 2020Àwọn BàhámàIkúMicrosoftSunita WilliamsAustrálíàLinuxAfeez OwóMọ́skòWikipẹ́díà l'édè YorùbáISO 3166-1Pópù Adrian 3kÌlaòrùn ÁfríkàIron17 AprilÒgún LákáayéLadi KwaliFenesuelaParisiIfáAaliyah(7123) 1989 TT1YorùbáIléAtlantaMariam Alhassan AloloDonald TuskISO 639-31168 BrandiaUnited NationsÌgbéyàwóOmiEre idarayaYukréìnZuluỌ̀yọ́túnjíOṣù Kejì25 JulyÀkàyéZDélé Mọ́mọ́dù.jpÌwé Àṣẹ Aṣàlàyé Ọ̀fẹ́ GNUErin-Ijesha WaterfallsÈdè Faransé27 JuneṢàngóÒrìṣà EgúngúnNse Ikpe-EtimSístẹ́mù ajọfọ̀nàkò jẹ́ọ́gráfìOSI modelOsorkon🡆 More