Àdàkọ:Contains Japanese text Matsuo Bashō (松尾 芭蕉?, 1644 – November 28, 1694), abiso Matsuo Kinsaku (松尾 金作?), nigbana bi Matsuo Chūemon Munafusa (松尾 忠右衛門 宗房?), je akoewi togbajumojulo ni igba Edo ni Japan.
Nigba aye re, Bashō gbajumo fun awon ise re ninu iru collaborative haikai no renga alajobarasepo; loni, leyin opo orundun awiso lori ise re, o gbajumo bi oga ninu haiku soki ati kedere. Awon ewi re gbajumo kakiri aye.
Matsuo Bashō (松尾 芭蕉) | |
---|---|
Pen name | Sōbō (宗房) Tōsē (桃青) Bashō (芭蕉) |
Iṣẹ́ | Poet |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Japanese |
Notable works | Oku no Hosomichi |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Matsuo Bashō, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.