Màlúù

Màlúù takọ tabo ni wọ́n wọ́pọ̀ láàrin àwọn ẹranko ọ̀sìn ilé.

Wọ́n jẹ́ ọ̀kan lára ìsọ̀rí ẹbí àwọn ẹranko tí a mọ̀ sí Bovinae, tí wọ́n wọ́pọ̀ ju màlúù kẹ̀tẹ̀ àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.

Màlúù
Cattle
Màlúù
A Swiss Braunvieh cow wearing a cowbell
Ipò ìdasí
Ọ̀sìn
Ìṣètò onísáyẹ́nsì [ edit ]
Ìjọba: Animalia (Àwọn ẹranko)
Ará: Chordata
Ẹgbẹ́: Mammalia (Àwọn afọmúbọ́mọ)
Ìtò: Oníka-dídọ́gba
Ìdílé: Bovidae
Subfamily: Bovinae
Ìbátan: Bos
Irú:
B. b. taurus
Ìfúnlórúkọ méjì
Bos bos taurus
Linnaeus, 1758
Subspecies
  • Bos taurus indicus
  • Bos taurus taurus
Màlúù
Bovine range
Synonyms
  • Bos primigenius
  • Bos indicus
  • Bos longifrons

Ìwúlò Màlúù

Wọ́n sábà ma ń rè tàbí sin màlúù gẹ́gẹ́ bí ohun ọ̀sìn fún jíjẹ, pípèsè ẹran, fífi awọ rẹ̀ ṣe pànmọ́, ohun tí a lè fi pèsè wàrà, wọ́n ń lò wọ́n fún kíkọ ebè oko, lílo ìgbẹ́ rẹ̀ fún ajílẹ̀, tí ọ̀pọ̀ níní àwọn ẹ̀yà kan ní ilẹ̀ India ma ń sìn ín gẹ́gẹ́ bí òrìṣà tabí ọlọ́run wọn. According to an estimate from 2011, there are 1.4 billion cattle in the world..

Àwọn ìtọ́kasí

Tags:

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

José Miguel de Velasco FrancoÀṣà Ìsọmọ-lórúkọ nílẹ̀ YorùbáWolfgang PaulOhioJapanHassiomuÌṣiṣẹ́àbínimọ́.biParisiOgun Àgbáyé Ẹlẹ́ẹ̀kejìEugenio MontaleISO 3166-2Aung San Suu Kyi22 FebruaryAta ṣọ̀mbọ̀TòmátòÀdírẹ́ẹ̀sì IPLos Angeles1168 BrandiaÒrò àyálò YorùbáÀsà Ìgbéyàwó ní ilè YorùbáÀwọn Ọba Ilẹ̀ YorùbáFrans Eemil SillanpääÈdè Esperanto.gu7082 La SerenaYorùbáMalek JaziriSobekneferuÀwùjọỌ̀yọ́túnjíJohn MiltonIlé-Ifẹ̀27 NovemberPólàndìCliff RobertsonSílíkọ́nù8 SeptemberIṣẹ́ ọnà22 OctoberVFrederick Lugard24 OctoberFaithia BalogunSQL22 March.cdÌwé Málákì.so10 JulyAaliyah30 OctoberÌgbà EléèédúMársìÀàrẹ ilẹ̀ Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà.naB.L. AfakiryeQueen's CounselBùrúndìGSérbíà àti MontenégròDiamond Jackson🡆 More