Àwọn ẹ̀rànkòrónà jẹ́ àwọn èràn tọ́ ń kó àrùn ran àwọn ẹranko afọ́mọlọ́yàn bíi ènìyàn, àti àwọn ẹyẹ.
Bí ó bá jẹ́ ènìyàn, Coronavirus tàbí Koronafáírọ́ọ̀sì yìí a máa fa àrùn sí àwọn ẹ̀yà ara inú tí ènìyàn fi ń mí, tí ó sìn lè pànìyàn kíákíá. Ó lè fa irú àrùn yìí tàbí ìgbẹ́-gbuuru (diarrhea) fún ẹyẹ, Ẹlẹ́dẹ̀ tàbí Màlúù. Lọ́wólọ́wọ́ báyìí kò sí ẹ̀rọ̀ tàbí oògùn ìwòsàn tàbí Ìdènà tí ó lè wo àrùn tí Coronavirus yìí máa ń fà.
Orthocoronavirinae | |
---|---|
Electron micrograph of coronavirus virions | |
Ìṣètò ẹ̀ràn [ e ] | |
(unranked): | Èràn |
Realm: | Riboviria |
Ará: | Incertae sedis |
Ìtò: | Nidovirales |
Ìdílé: | Coronaviridae |
Subfamily: | Orthocoronavirinae |
Genera | |
| |
Synonyms | |
|
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Èrànkòrónà, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.