Kẹ́místrì

Ìpògùn tí ṣe ẹ̀ka sáyẹ́nsì oníṣeẹ̀dá, jẹ́ ẹ̀kọ́ìwádìí ìkósínú, ìní àti ìwùwà ohun èlò.

Kẹ́místrì únsọ nípa àwọn átọ́mù àti ìbáraṣepọ̀ wọn pẹ̀lú àwọn átómù míràn, àgàgà pẹ̀lú àwọn ìní àwọn ìsopọ̀ kẹ́míkà. Kẹ́místrì tún úndálórí àwọn ìbáraṣepọ̀ láàrin àwọn átọ́mù (tàbí ọ̀pọ̀ àwọn átọ́mù) àti orísirísi irú okun (f.a. àwọn ìdaramọ́ra f fọ́tòkẹ́míkà, àwọn ìyípadà nínú ojúwà èlò, ìyàsọ́tọ̀ àwọn àdàlú, àwọn ìní pólímẹ̀r, at.b.b,lọ).

Kẹ́místrì
Chemicals in flasks (including Ammonium hydroxide and Nitric acid) lit in different colors

Kẹ́místrì únjẹ́ pípè nígbà míràn bíi "sáyẹ́nsì agbàrin" nítorípé ó so ìṣeẹ̀dá mọ́ àwọn sáyẹ́nsì onítaládánidá míràn bíi Jẹ́ọ́lọ́jì àti baolọ́jì. Kẹ́místrì jẹ́ ẹ̀ka sáyẹ́nsì oníṣeẹ̀dá sùgbọ́n ó yàtọ̀ sí físíksì.

Ìtumọ̀-ọ̀rọ̀

Ìtàn

Àwọn òpó ìpògùn òdeòní

Èlò

Átọ́mù

Àkọ́bẹ̀rẹ̀

Àdàpọ̀

Ounkókó

Hóró

Mólù àti iye àwọn ounkókó

Àwon ìní

Àwọn íónì àti iyọ̀

Ìjẹ́kíkan àti ìjẹ́ipìlẹ̀

Ojúìwà

Ìsopọ̀

Ìtúnṣe

Rẹ́dọ́ksì

Àyèdídọ́gba

Okun

Àwọn òfin àpòpọ̀ògùn

Àwọn ìtúnṣe àpòpọ̀ògùn ní àwọn òfin dájú tó ṣàkóso wọn, tí wọ́n ti dí òye àpilẹ̀sẹ̀ nínú ìpògùn. Díẹ̀ nínú wọn nìyí:

  • Òfin Avogadro
  • Òfin Beer-Lambert
  • Òfin Boyle (1662, tó ṣe ìbáṣepọ̀ ìfúnpá àti ìkún)
  • Òfin Charles (1787, tó ṣe ìbáṣepọ̀ ìkún àti ìgbónásí)
  • Òfin ìtúsí Fick
  • Òfin Gay-Lussac (1809, tó ṣe ìbáṣepọ̀ ìfúnpá àti ìgbónásí)
  • Òpó Le Chatelier
  • Òfin Henry
  • òfin Hess
  • Law of conservation of energy leads to the important concepts of equilibrium, thermodynamics, and kinetics.
  • Law of conservation of mass continues to be conserved in isolated systems, even in modern physics. However, special relativity shows that due to mass-energy equivalence, whenever non-material "energy" (heat, light, kinetic energy) is removed from a non-isolated system, some mass will be lost with it. High energy losses result in loss of weighable amounts of mass, an important topic in nuclear chemistry.
  • Law of definite composition, although in many systems (notably biomacromolecules and minerals) the ratios tend to require large numbers, and are frequently represented as a fraction.
  • Law of multiple proportions
  • Raoult's Law

Ẹ tún wo


Itokasi

Àdàkọ:Ìbọ̀sẹ̀ sáyẹ́nṣì onítaládánidá

Tags:

Kẹ́místrì Ìtumọ̀-ọ̀rọ̀Kẹ́místrì ÌtànKẹ́místrì Àwọn òpó ìpògùn òdeòníKẹ́místrì Ẹ tún woKẹ́místrì ItokasiKẹ́místrìChemical bondÁtọ́mù

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Austrálíà.alInternational Standard Book NumberDavid Beckham13 MayInternetÀgùtànRepublican Party (United States)Délé Mọ́mọ́dù.geAgbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ido-OsiÀlọ́YorùbáBostonTẹlifísànErin-Ijesha WaterfallsCaliforniaBobriskyNancy ChartonỌ̀gbìnGùyánà FránsìCharlemagneEhoroTibetCD-ROMIlẹ̀gẹ̀ẹ́sìAjáJulian Schwinger22 SeptemberEugenio MontalePhoebe EbimiekumoRwandaShehu Abdul Rahman.saKọ̀mpútàHilary SwankNọ́mbà tíkòsíISO 3166-1Pópù Felix 3kÀwọn ÁràbùỌ́ksíjìn4363 SergejÀkàyé7 AprilSanusi Lamido SanusiGlobal Positioning SystemAminu Ado BayeroRembrandtFrancisco FrancoÀsìá ilẹ̀ KánádàÀsà oge ṣíṣẹ́ ní ilè yorùbáTaofeek Oladejo ArapajaLáọ̀sWikimediaAfghanístànMontana🡆 More