Oṣù Ṣẹ̀rẹ́

Oṣù Ṣẹ̀rẹ́ tàbí oṣù Kìíní jẹ́ oṣù àkọ́kọ́ nínú Kàlẹ́ńdà Gregory.

Ọjọ́ mọ́kànlélọ́gbọ̀n ni ó wà nínú osù yìí. Ọjọ́ kìíní ti oṣù Ṣẹ̀rẹ́ ni a ṣe ayẹyẹ ọdún títun. Ní ìpíndọ́gba, oṣù yìí sì jẹ́ oṣù tí ó máa ń tutú jù lọ ní ìdajì ayé àríwá (nítorí pé ó jẹ́ oṣù kejì ti ìgbà òtútù níbẹ̀); ó sì jẹ́ oṣù tí ooru máa ń mú jù lọ ní ìdajì ayé gúúsù (nítorí pé ó jẹ́ oṣù kejì ti ìgbà sọ́mà níbẹ̀). Ní èdè Gẹ̀ẹ́sì, wọ́n pè é ní "January"; orúkọ yìí wá láti ọ̀rọ̀ èdè Látínì "iānuārius" (osù ti Janus). Nítorí èyí, ní èdè Yorùbá náà a sì máa ń pe oṣù yìí ní "oṣù Jánúárì" ní ìgbà mìíràn, ṣùgbọ́n ọ̀pọ̀ ènìyàn máa ń wí pé kò yẹ́ kí a lò ó nítorí jíjẹ́ ọ̀rọ̀-àyálò tí ó jẹ́.

Oṣù Ṣẹ̀rẹ́
kalẹnda ti oṣu kini
Oṣù Kínní
Àìkú Ajé Ìsẹ́gun Ọjọ́rú Ọjọ́bọ̀ Ẹtì Àbámẹ́ta
1 2 3 4 5 6
7 8 9 10 11 12 13
14 15 16 17 18 19 20
21 22 23 24 25 26 27
28 29 30 31
 
2024
Osù:| Kínní | Kejì | Kẹta | Kẹrin | Kàrún | Kẹfà | Keje | Kẹjọ | Kẹ̀sán | Kẹ̀wá | Kọkànlá | Kejìlá

Tags:

Kalenda GregoryOsùÈdè Gẹ̀ẹ́sì

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Àwọn Ẹ̀ka-èdè Yorùbá4363 SergejFile Transfer ProtocolBaskin-RobbinsPakístànISO 8601Ẹkún ÌyàwóÌwọ́ ìtannáTheodor HeussFrançois FillonRonald ColmanTibetMercedes-BenzSudanYemoja17 April7 AprilGiya KancheliPrologElvis PresleyÈdè TúrkìKenneth ArrowSpéìnMalek Jaziri27 NovemberRobert B. Laughlin18946 MassarHerbert MacaulayKòréà ÀríwáInternet22 SeptemberCopenhagenInternational Standard Book NumberBill ClintonÍslándìGbólóhùn YorùbáYunifásítì HarvardISO 3166-12 JuneMùsùlùmíỌ̀rọ̀ayéijọ́un.kyMassachusettsÁrktìkìHassiomuFránsì7 OctoberAnkara2 SeptemberOlu JacobsUSAHTMLÈdè IjọLéon M'baÌbálòpọ̀Apágúúsù ÁfríkàAloma Mariam MukhtarHilary Swank10 AprilUnited NationsIfá🡆 More