Ọjọ́ Ajé

Ọjọ́ ajé jẹ ọjọ́ tí ó wà láàrin ọjọ́ àìkú àti ọjọ́ ìṣẹ́gun.

Gégé bí àjọ International Organization for Standardization's ISO 8601 se sọ, ọjọ́ ajé ni ọjọ́ àkọ́kọ́ nínú ọ̀sẹ̀, àwọn orílẹ̀-èdè míràn tí ó ka ọjọ́ àìkú sí ọjọ́ àkókò inú ọ̀sẹ̀ sì ka ọjọ́ ajé sí ọjọ́ kejì inú ọ̀sẹ̀. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ èdè ni ó sọ ọjọ́ ajé ní orúkọ tẹ̀lé òṣùpá.

Ọjọ́ Ajé
àwòrán Galileo nípa òṣùpá ní ọdún 1616. Wọ́n sọ ọjọ́ ajé ní orúkọ tẹ̀lẹ́ òṣùpá ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ èdè.

Ipò láàrin ọ̀sẹ̀

Ní ayé àtijó, ọ̀sẹ̀ àwọn Gíríìkì àti Róòmù bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ọjọ́ àìkú(dies solis), tí ọjọ́ ajé sì jẹ́ ọjọ́ kejì ọ̀sẹ̀(dies lunae). Bẹ́ẹ̀ tún ni, ní ariwa America, wón ka ọjọ́ àìkú sí ọjọ́ àkọ́kọ́ inú ọ̀sẹ̀. Ṣùgbọ́n

International Organization for Standardization fi ọjọ́ ajé sí ipò àkọ́kọ́ nínú ọ̀sẹ̀ ní ISO 8601. Àwọn ará China ma ń pe ọjọ́ ajé ní xīngqīyī (星期一) èyí tí ó túmọ̀ sí "ọjọ́ àkọ́kọ́ ọ̀sẹ̀".

Ìbọ̀wọ̀ àwọn ẹṣin fún ọjọ́ ajé

Ẹ̀sìn Kristẹni, islam àti Judaism ka ọjọ́ ajé sí ọjọ́ tí ó wà fún àwẹ̀. Àwọn Hadith kọ̀kan wípé ọjọ́ ajé jẹ́ ọjọ́ tí wón bí Muhammadu, ọjọ́ ajé ṣì ní ọjọ́ tí ó rí ìṣípayá rẹ̀ àkọ́kọ́, èyí tí ó padà di Quran.

Àwọn Ìtókasí

Tags:

ISO 8601International Organization for StandardizationỌjọ́Ọ̀sẹ̀

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

ISO/IEC 8859-16Frederica WilsonBobriskyISO 15926 WIPHope Waddell Training InstituteMandy MinellaBiodun JeyifoISO/IEC 10967Àwọn orin ilẹ̀ YorùbáÀsìá ilẹ̀ Singapore.yeISO 639ISO 14644-2Wiki Commons.vg(9981) 1995 BS3TX.500Hypertext Transfer ProtocolMọ́remí Ájàṣoro.ukISO 14644-8Pablo PicassoAlice Brady67085 OppenheimerUnited Nations Development Programme918 IthaÀjákálẹ̀ àrùn káàkiriayé èrànkòrónà ọdún 2019 2020RELAX NGỌbàtáláISO 14698-2ISO 639-1San FranciscoÀrún èrànkòrónà ọdún 2019ISO 31-10Brazzaville.inKárbọ̀nù.gwAdams OshiomholeRihannaISO 14971Charles Glover BarklaOlógbòÌjẹ̀bú-ÒdePennsylvaniaAṣọ2022Elisabeti KejìRita HayworthISO 10962.maÀjàkálẹ̀ àrùn COVID-19 ní ilẹ̀ NàìjíríàISO 233LBíbélì Mímọ́Ìbálòpọ̀SARS-CoV-2Pópù Jòhánù 17k.iqISO/IEC 27004Rabindranath TagoreISO 13584TẹlifóònùÀwọn Òpó Márùún ÌmàleISO 14644-7Burkina FasoÈlòISO 22000🡆 More