Ẹ̀bùn Ọ́skà

Àwọn Ẹ̀bùn Akádẹ́mì tàbí Ẹ̀bùn Ọ́skà jẹ́ ẹ̀bùn ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ fíìmù tí American Academy of Motion Picture Arts and Sciences ma ń fún olùdarí eré, òṣèrè àtí olùkọ̀tàn fún iṣẹ́ takuntakun ní ilé iṣẹ́ fíìmù.

Ayẹyẹ ẹ̀bùn yìí jẹ́ ìkan lára àwọ́n ayẹyẹ èbùn tó lókìkí jùlọ ní gbogbo àgbáyé. Osì tún jẹ́ Ayẹyẹ ẹ̀bùn tó pẹ́ júlọ tí ó si ma ń dàgbeléwò lórí ẹ̀rọ amóùnmáwòran ní orílẹ̀ èdè tó ju igba lọ. Aẁọn ẹ̀bùn ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ fíìmù bi tiẹ̀ ni Grammy Awards (fún orin), Emmy Awards (fun amóùnmáwòran), àti Tony Awards (fún tíát̀à)

Ẹ̀bùn Ọ́skà
Ẹ̀bùn Ọ́skà
Ère ẹ̀bùn ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ fíìmù Amẹ́ríkà
Bíbún fún fún iṣẹ́ takuntakun ní ilé iṣẹ́ fíìmù Améríkà
Látọwọ́ Academy of Motion Picture Arts and Sciences
Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà
Bíbún láàkọ́kọ́ May 16, 1929
Ibiìtakùn oníbiṣẹ́ Oscars.org

Ìtọ́kasí

Tags:

Grammy Awards

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Àwọn Òpó Márùún Ìmàle22 DecemberSeattleAkanlo-edeHuman Rights FirstMurtala MuhammadÀrún èrànkòrónà ọdún 201923 JuneLẹ́tà gbẹ̀fẹ̀Ilẹ̀ Ọba BeninÀríwá Amẹ́ríkàFísíksìÒrò àyálò YorùbáMaseruThomas CechOgun Àgbáyé Ẹlẹ́ẹ̀kejìKọ̀mpútàÒgún LákáayéJapanAdaptive Multi-Rate WidebandVictor Thompson (olórin)Dejumo LewisÌran Yorùbá67085 OppenheimerẸ̀sìnVladimir NabokovCaracasGoogleÀwọn orin ilẹ̀ YorùbáÌwéTashkentÀjákálẹ̀ àrùn káàkiriayé èrànkòrónà ọdún 2019 2020Walter MatthauMọ́remí ÁjàṣoroOctave MirbeauPópù Gregory 16kÀkójọ àwọn olórí orílẹ̀-èdè ilẹ̀ NàìjíríàÌpínlẹ̀ Ògùn2024LebanonÀàrẹ ilẹ̀ Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkàÌpínlẹ̀ ÈkóÌpínlẹ̀ ÈkìtìFile Transfer ProtocolItan Ijapa ati AjaKarachiÀmìọ̀rọ̀ QR🡆 More