Íónì je atomu tabi horo kan ni inu ibi ti iye apapo awon elektronu ko dogba mo iye apapo awon protonu, bi be ti atomu na yio ni agberu itanna to seku to je didaju tabi lilodi.
Ioni wa lati oro ede Griiki ἰόν (to tumosi "o rinso"), o si koko je lilo latowo asefisiksi Michael Faraday fun awon ohun ti won unlo labe iwo itanna larin awon elektrodu ninu iyosomi kan, nigbati ayika itanna kan ba je mimulo mo.
Ti atomu adogba kan ba pofo elektronu kan tabi jubelo, yio ni agberu siseku didaju, eyi ni a unpe ni kationi. Ti atomu kan ba jere elektronu, yio ni agberu siseku lilodi, a si unpe ni anioni. Ioni kan to ni atomu kan soso ni a unpe ni ioni atomu tabi oniatomukan; to ba ni atomu meji tabi jubelo, a unpe ni ioni onihoro tabi oniatomupupo.
Ninu apere isodiioni efuufu kan, awon ohun kan ti a unpe ni "ibeji ioni" je dida ti won ni elektronu adawa kan ati ioni didaju kan.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Íónì, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.