Václav Havel (Àdàkọ:IPA-cs) (5 October 1936 – 18 December 2011) je Tseki olukereitage, alaroko, alakitiyan ati oloselu.
Ohun ni eni ikewa ati to gbeyin bi Aare ile Czechoslovakia (1989–92) ati eni akoko bi Aare ile Tseki Olominira (1993–2003). O ti ko ere itage to ju ogun lo ati awon iwe miran ti won ti je yiyiledepada kakiriaye. O gba Eso Aare fun Ominira ti Amerika, Eso Ominira Filadelfia, Enioto ile Kanada, ati Olusoju Ebun Eriokan. Bakanna ni 2005 o je didiboyan bi eni omowe 4th nini ibo gbogbo aye ti iwe olosoosu Prospect Magazine se larin awon omowe 100 olokiki julo.
Václav Havel | |
---|---|
1st President of the Czech Republic | |
In office 2 February 1993 – 2 February 2003 | |
Alákóso Àgbà | Václav Klaus Josef Tošovský Miloš Zeman Vladimír Špidla |
Asíwájú | Position established |
Arọ́pò | Václav Klaus |
10th President of Czechoslovakia | |
In office 29 December 1989 – 20 July 1992 | |
Alákóso Àgbà | Marián Čalfa Jan Stráský |
Asíwájú | Gustáv Husák |
Arọ́pò | Position abolished |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Prague, Czechoslovakia (now Czech Republic) | 5 Oṣù Kẹ̀wá 1936
Aláìsí | 18 December 2011 Hrádeček, Czech Republic | (ọmọ ọdún 75)
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Independent Civic Forum (1989–1993) |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Olga Šplíchalová (1964–1996) Dagmar Veškrnová (1997–2011; his death) |
Alma mater | Czech Technical University in Prague Faculty of Theatre |
Profession | Playwright |
Signature | |
Website | www.vaclavhavel.cz www.vaclavhavel-library.org |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Václav Havel, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.