Harold George Harry Belafonte, Jr.
O je pipe bi "Oba Orin Calypso" fun imugbajumo iru orin Caribbean kakiri aye ni ewadun 1950. Belafonte gbajumo fun kiko orin "The Banana Boat Song", pelu igbe-orin "Day-O." Kakiri ise re o je agbejero fun eto araalu ati ija omoniyan.
Harry Belafonte | |
---|---|
Belafonte at the 2011 Tribeca Film Festival Vanity Fair party | |
Background information | |
Orúkọ àbísọ | Harold George Bellanfanti, Jr. |
Ọjọ́ìbí | Oṣù Kẹta 1, 1927 Harlem, New York, U.S. |
Irú orin | Calypso, vocal, folk |
Occupation(s) | Actor, activist, singer |
Years active | 1949–2003 |
Labels | RCA Victor CBS EMI Island |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Harry Belafonte, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.