2023: Ọdún tí a wà lọ́wọ́ nínú kàlẹ́ndà Gìrẹ́górì

◄ | Ọ̀rúndún 20k | Ọ̀rúndún 21k     ◄◄ | ◄ | 2019 | 2020 | 2021 | 2022 | 2023 | 2024          


Odun 2023 jẹ́ ọ̀kan nínú ọdún nínú kàlẹ́ndà Gìrẹ́górì. Ọdún 2023 bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ọjọ́ Àìkú nínú kàlẹ́ndà Gìrẹ́górì.

Àwọn ìṣẹ̀lẹ̀

Oṣù kínní

  • Ọjọ́ kẹjọ oṣù kínní(Jan 8)
    • Àjàkáyé-àrùn Covid 19: Orílè-èdè China ṣí ààlà ilẹ̀ wọn fún àwọn àlejò láti orílè-èdè míràn, èyí jẹ́ òpin sí fífi òfin de àwọn ìrìn àjò kọ̀kan èyí tí ó bẹ̀rẹ̀ ní oṣù kẹta ọdún 2020.
    • Ìdìbọ̀ sí ilé ìgbìmò asofin ti orílè-èdè Benin wáyé.
  • Ọjọ́ kẹtàlá sí ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kínní(Jan 13Jan 14) – Ipele àkọ́kọ́ ti Ìdìbọ̀ ààrẹ orílè-èdè Czech wáyé.
  • Ọjọ́ keedogun oṣù kínní(Jan 15)– Ọkọ̀ bàlúù kan tí wón ń pè ní Yeti Airlines Flight 691 já ní Pokhara, orílè-èdè Nepal, ó sì pa ó kéré jù, ènìyàn kandinladorin.
  • Ọjọ́ kerindínlógún oṣù kínní(Jan 16) – Ọwọ́ ìjọba orílè-èdè Italy tẹ olórí ẹgbẹ jàndùkú kan tí wón ti ún wá fún ọjọ́ pípé, Matteo Messina Denaro ní Palermo, Sicily.
  • Ọjọ́ kẹtàdínlógún oṣù kínní (Jan 17) – Nguyễn Xuân Phúc kọ̀wé fisẹ́ sílẹ̀ gẹ́gẹ́ bi ààrẹ orílè-èdè Vietnam lẹyìn ọ̀pọ̀lopọ̀ ìwóde ìfẹ̀hónúhàn tako àwọn àìsedédé ìjọba rẹ̀.
  • Ọjọ́ ogún oṣù kínní(Jan 20)– Àwọn asọ̀fin orílè-èdè Trínídád àti Tòbágò yan Christine Kangaloo gẹ́gẹ́ bí Ààrẹ Orílẹ̀-èdè náà.
  • Ọjọ́ keedogbon oṣù kínní(Jan 25)– Chris Hipkins rọ́pò Jacinda Ardern gẹ́gẹ́ bi Mínísítà àgbà orílè-èdè New Zealand, ọjọ́ mefa lẹ́yìn tí Jacinda Ardern kọ̀wé fi ipò mínísítà àgbà sílè.
  • Ọjọ́ kẹtàdínlógbọ̀n sí ọjọ́ kejìdínlógbọ̀n oṣù kínní (Jan 2728) – Ipele kejì Ìdìbọ̀ ààrẹ orílè-èdè Czech ọdun 2023 wáyé, Petr Pavel ni ó jáwé olúborí.

Oṣù Kejì

Oṣù kẹta

Ótún le ka

Àwọn Ìtókasí

Tags:

2023 Àwọn ìṣẹ̀lẹ̀2023 Ótún le ka2023 Àwọn Ìtókasí2023202120222024Ọ̀rúndún 21k

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Ìbánisọ̀rọ̀-ọ̀ọ́kánÌsirò StatistikiMaseruOjúewé Àkọ́kọ́Ogun Àgbáyé KìíníKàlẹ́ndà Gregory(213893) 2003 TN2Octave MirbeauRichard NixonÀjẹsára Bacillus Calmette–GuérinDejumo LewisVictor Thompson (olórin)Ilẹ̀ YorùbáWikimediaOwe YorubaLyndon B. JohnsonÌpínlẹ̀ ÈkóIÈṣùFilipínìẸyẹGoogle23 JuneJapanAustríàMicrosoftOlúṣẹ́gun Ọbásanjọ́Isiaka Adetunji AdelekeÀkójọ àwọn olórí orílẹ̀-èdè ilẹ̀ NàìjíríàThe New York TimesÀṣà Ìsọmọ-lórúkọ nílẹ̀ YorùbáWolframuJack LemmonJakarta1490 LimpopoPornhubỌbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀BobriskyÌtànRọ́síàEhoroAbdulaziz UsmanPópù Benedict 16kÈdè YorùbáWater67085 OppenheimerTashkentBarry WhiteLiberiaISO 3166-1 alpha-2CalabarÌgbéyàwóBarbara SokyIfáGlobal Positioning SystemOgun Àgbáyé Ẹlẹ́ẹ̀kejìÀwọn orin ilẹ̀ YorùbáÀrokòBoris Yeltsin🡆 More