Iṣẹ́ẹ̀rọ Onítanná

Iṣẹ́ẹ̀rọ onítanná (Electrical engineering) ni papa eko iseero to un da lori agbeka ati imulo itanna, isiseonina ati iseonigberingberin onina.

Papa eko yi koko di ise sise ni opin orundun okandinlogun leyin isodidunadura telegrafu itanna ati ipese agbara onitanna. Loni o ti de oro bi agbara, isiseonina, awon sistemu ijannu, igbese alamioro ati awon ibanisoroelero.

Iṣẹ́ẹ̀rọ Onítanná
Àwọn oníṣẹ́ẹ̀rọ onítanná úndá àwọn sístẹ́mù agbára aṣòro...
Iṣẹ́ẹ̀rọ Onítanná
...àti àwọn àsoyípo oníná.

Iseero onitanna le tun je mo iseero onina. Iseero onitanna je gbigba pe o da lori awon isoro to je mo awon sistemu onitanna gbangba bi ifiranse agbara itanna ati ikojannu oko, nigbati iseero onina da lori agbeka awon sistemu onina kekere bi komputa ati awon asoyipo olodidi. Tabi, a le so pe awon oniseero onitanna unda ise won lori lilo itanna lati fi safiranse okun onitanna, nigbati awon oniseero onina unda ise won lori lilo itanna lati se igbese aroye. Loni, ko fi be si iyato larin awon mejeji nitori idagbasoke to ti ba isiseonina agbara.


Ẹ tún wo

Itokasi

Ajapo ode

Àdàkọ:Wikibooks Àdàkọ:WVD Àdàkọ:Wikiversity

Tags:

ElectricityElectronicsTelecommunication

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

W. E. B. Du BoisBostonAwonYeni KutiHugo ChávezBaton RougeSonyNew ZealandCleveland, OhioEstóníàGbólóhùn YorùbáÈdè FiẹtnámPópù Paschal 1kMona BarthelPópù Gregory 13kHawaiiMarsLiza MinnelliKùwéìtìWalter ScheelSt. George's, Grẹ̀nádàVietJet AirMario BooysenÌtàn ilẹ̀ Siẹrra LéònèChanel SimmondsÀwọn ará Jẹ́mánìWallis and FutunaPópù Sylvester 1kIṣuÀríwá Amẹ́ríkàÌjàmbá ìtúká ẹ̀búté Bèírùtù ọdún 2020ArgẹntínàÀjàkáyé-àrùnYukréìnJacksonvilleṢìkágòÀrokòParisiNoynoy AquinoÀsà oge ṣíṣẹ́ ní ilè yorùbáIsaac NewtonOrin Rhythm and bluesÈkóÀmì ọ̀pá àṣẹ ilẹ̀ IndonésíàVladimir LeninPópù Marcellus 2kÁntígúà àti BàrbúdàJoão GoulartÈdè Gẹ̀ẹ́sìLudwig van BeethovenDresdenỌ̀rọ̀-Orúkọ (Èdè Yorùbá)MadagásíkàSebastián PiñeraÌlàòrùn TimorIstanbulDram ArméníàÌwọ̀orùn Jẹ́mánìÌṣọ̀kan EuropeÌwọòrùn Bẹ̀ngálWoody AllenTheodore RooseveltÒkun DúdúGeorges CharpakC SharpPópù Alexander 7kBenuAmerika (orile)Dẹ́nmárkìBarack ObamaAbdullah ilẹ̀ Sáúdí ArábíàIyánCleopatra VIIAlan Turing🡆 More