Húngárì (i /ˈhʌŋɡəri/; Àdàkọ:Lang-hu Àdàkọ:IPA-hu), lonibise bi Orileominira Hungari (Hungarian: Magyar Köztársaság listen (ìrànwọ́·ìkéde)), je orile-ede kan tileyika ni Arin Gbongan Europe.
O budo sinu Iwolejo Pannoni o si ni bode mo Slovakia ni ariwa, Ukraine ati Romania ni ilaorun, Serbia ati Croatia ni guusu, Slovenia ni guusuiwoorun ati Austria ni iwoorun. Oluilu ati ilu totobijulo re ni Budapest. Hungary je orile-ede omo egbe Isokan Europe, NATO, OECD, ati Egbe Visegrád. Ede onibise ibe ni ede Hungari, to je ikan ninu awon ede Ural be sini o je ee to gbalejulo ti ki se ede Indo-Europe ni Europe.
Orílẹ̀òmìnira Húngárì Republic of Hungary Magyar Köztársaság | |
---|---|
Motto: none Historically Látìnì: Cum Deo pro Patria et Libertate ("With the help of God for Homeland and Freedom") or [Regnum Mariae Patronae Hungariae] error: {{lang}}: text has italic markup (help) ("Kingdom of Mary, the Patron of Hungary" | |
Ibùdó ilẹ̀ Húngárì (dark green) – on the European continent (light green & dark grey) | |
Olùìlú àti ìlú tótóbijùlọ | Budapest |
Àwọn èdè ìṣẹ́ọba | Hungarian; Hungarian Sign Language |
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn | 95% Magyar, 2% Roma, 3% other minority groups |
Orúkọ aráàlú | Hungarian |
Ìjọba | Parliamentary republic |
• President | Tamás Sulyok |
• Prime Minister | Viktor Orbán |
Aṣòfin | Országgyűlés |
Foundation | |
• Foundation of Hungary | 896 |
• Recognized as Kingdom - First king: Stephen I of Hungary | December 1000 |
• Currently 3rd Republic | October 23, 1989 |
Ìtóbi | |
• Total | 93,030 km2 (35,920 sq mi) (109th) |
• Omi (%) | 0.74% |
Alábùgbé | |
• 2009 July estimate | 10,020,000 (79th) |
• 2001 census | 10,198,315 |
• Ìdìmọ́ra | 107.7/km2 (278.9/sq mi) (94th) |
GDP (PPP) | 2008 estimate |
• Total | $196.417 billion (51st) |
• Per capita | $19,553 (44th) |
GDP (nominal) | 2008 estimate |
• Total | $155.930 billion. (52nd) |
• Per capita | $15,522 (44th) |
Gini (2008) | 24.96 low · 3rd |
HDI (2007) | ▲ 0.879 Error: Invalid HDI value · 43rd |
Owóníná | Forint (HUF) |
Ibi àkókò | UTC+1 (CET) |
• Ìgbà oru (DST) | UTC+2 (CEST) |
Irú ọjọ́ọdún | yyyy.mm.dd, yyyy.mm.dd (CE) |
Ojúọ̀nà ọkọ́ | right |
Àmì tẹlifóònù | 36 |
Internet TLD | .hu1 |
|
Following a Celtic (after c. 450 BC) and a Roman (9 AD – c. 430 AD) period, the foundation of Hungary was laid in the late 9th century by the Hungarian ruler Árpád, whose great-grandson Saint Stephen I was crowned with a crown sent from Rome by the pope in 1000 AD. The Kingdom of Hungary lasted for 946 years, and at various points was regarded as one of the cultural centers of the Western world. After about 150 years of partial Ottoman occupation (1541–1699), Hungary was integrated into the Habsburg Monarchy, and later constituted half of the Austro-Hungarian dual monarchy (1867–1918). A great power until the end of World War I, Hungary lost over 70% of its territory, along with one third of its population of Hungarian ethnicity, and all sea ports under the Treaty of Trianon, the terms of which have been considered excessively harsh by many in Hungary. The kingdom was succeeded by a Communist era (1947–1989) during which Hungary gained widespread international attention regarding the Revolution of 1956 and the unilateral move of opening its border with Austria in 1989, thus accelerating the collapse of the Eastern Bloc. The present form of government is a parliamentary republic, which was established in 1989. Today, Hungary is a high-income economy and a regional leader in some regards.
Hungary is one of the thirty most popular tourist destinations of the world, attracting 8.6 million tourists per year (2007). The country is home to the largest thermal water cave system and the second largest thermal lake in the world (Lake Hévíz), the largest lake in Central Europe (Lake Balaton), and the largest natural grasslands in Europe (Hortobágy).
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Húngárì, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.