Dwayne Douglas Johnson (ojoibi May 2, 1972), to tun gbajumo pelu oruko ijaemu re The Rock, je osere, olootu, onisowo, ajaemu totifeyinti ati agbaboolu-elese ti Amerika ara Amerika .
O je ajaemu fun ile-ise World Wrestling Federation (WWF, loni bi WWE) fun odun mejo ko to di osere. Awon filmu re ti pawo to to US$3.5 billion ni Amerika ati US$10.5 billion lagbaye, to so di ikan ninu awon osere to pawo filmu julo ni gbogbo igba aye.
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Dwayne Johnson, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.