Bẹ́rílíọ̀mù

Bẹ́rílíọ̀mù ni ẹ́límẹ̀ntì kẹ́míkà tó ní àmì-ìdámọ̀ Be àti nọ́mbà átọ̀mù 4.

Nítorípé bẹ́rílíọ̀mù yíówù tó bá jẹ́ kíkódájọpọ̀ ní inú àwọn ìràwọ̀ kì í pẹ́ tí ó fi túká, nítoríẹ̀ ó jẹ́ ẹ́límẹ̀ntì tó sọ̀wọ́n gidigidi ní àgbàlá-ayé ati ní Ilẹ̀-Ayé. Ó jẹ́ ẹ́límẹ̀ntì olójú-ìsopọ̀ mẹ́jì tó ṣe é rí nínú ìdàpọ̀ mọ́ àwọn ẹ́límẹ̀ntì míràn nìkan nínú àwọn àlúmọ́nì. Àwọn òkúta iyebíye pàtàkì kan tí wọ́n ní bẹ́rílíọ̀mù nínú ni bẹ́rìlì (òkúta odò, ẹ́míràldì) àti bẹ́rìlìoníwúrà. Tó bá dá wà, ó jẹ́ ẹ́límẹ̀ntì mẹ́tàlì alkalínì ilẹ̀ tó ní àwọ̀ irin-idẹ, tó lágbára, fífúyẹ́ àti rírún wẹ́wẹ́.

Bẹ́rílíọ̀mù, 4Be
Bẹ́rílíọ̀mù
Bẹ́rílíọ̀mù
Pípè /bəˈrɪliəm/ (bə-RIL-ee-əm)
Ìhànsójúwhite-gray metallic
Ìwúwo átọ̀mù Ar, std(Be)9.0121831(5)
Bẹ́rílíọ̀mù ní orí tábìlì àyè
Hydrogen Helium
Lithium Beryllium Boron Carbon Nitrogen Oxygen Fluorine Neon
Sodium Magnesium Aluminium Silicon Phosphorus Sulfur Chlorine Argon
Potassium Calcium Scandium Titanium Vanadium Chromium Manganese Iron Cobalt Nickel Copper Zinc Gallium Germanium Arsenic Selenium Bromine Krypton
Rubidium Strontium Yttrium Zirconium Niobium Molybdenum Technetium Ruthenium Rhodium Palladium Silver Cadmium Indium Tin Antimony Tellurium Iodine Xenon
Caesium Barium Lanthanum Cerium Praseodymium Neodymium Promethium Samarium Europium Gadolinium Terbium Dysprosium Holmium Erbium Thulium Ytterbium Lutetium Hafnium Tantalum Tungsten Rhenium Osmium Iridium Platinum Gold Mercury (element) Thallium Lead Bismuth Polonium Astatine Radon
Francium Radium Actinium Thorium Protactinium Uranium Neptunium Plutonium Americium Curium Berkelium Californium Einsteinium Fermium Mendelevium Nobelium Lawrencium Rutherfordium Dubnium Seaborgium Bohrium Hassium Meitnerium Darmstadtium Roentgenium Copernicium Nihonium Flerovium Moscovium Livermorium Tennessine Oganesson
-

Be

Mg
lítíọ̀mù‎bẹ́rílíọ̀mùbórọ̀nù
Nọ́mbà átọ̀mù (Z)4
Ẹgbẹ́group 2 (alkaline earth metals)
Àyèàyè 2
Àdìpọ̀Àdìpọ̀-s
Ẹ̀ka ẹ́límẹ́ntì  Alkaline earth metal
Ìtò ẹ̀lẹ́ktrọ́nù[He] 2s2
Iye ẹ̀lẹ́ktrọ́nù lórí ìpele kọ̀ọ̀kan2, 2
Àwọn ohun ìní ara
Ìfarahàn at STPsolid
Ìgbà ìyọ́1560 K ​(1287 °C, ​2349 °F)
Ígbà ìhó2742 K ​(2469 °C, ​4476 °F)
Kíki (near r.t.)1.85 g/cm3
when liquid (at m.p.)1.690 g/cm3
Heat of fusion12.2 kJ/mol
Heat of 297 kJ/mol
Molar heat capacity16.443 J/(mol·K)
 pressure
P (Pa) 1 10 100 1 k 10 k 100 k
at T (K) 1462 1608 1791 2023 2327 2742
Atomic properties
Oxidation states0, +1, +2 Àdàkọ:Infobox element/symbol-to-oxidation-state/comment
ElectronegativityPauling scale: 1.57
energies
  • (more)
Atomic radiusempirical: 112 pm
Covalent radius96±3 pm
Van der Waals radius153 pm
Color lines in a spectral range
Color lines in a spectral range
Spectral lines of bẹ́rílíọ̀mù
Other properties
Natural occurrenceprimordial
Crystal structure ​hexagonal
Hexagonal crystal structure for bẹ́rílíọ̀mù
Speed of sound thin rod12870 m/s (at r.t.)
Thermal expansion11.3 µm/(m·K) (at 25 °C)
Thermal conductivity200 W/(m·K)
Electrical resistivity36 n Ω·m (at 20 °C)
Magnetic orderingdiamagnetic
Young's modulus287 GPa
Shear modulus132 GPa
Bulk modulus130 GPa
Poisson ratio0.032
Mohs hardness5.5
Vickers hardness1670 MPa
Brinell hardness600 MPa
CAS Number7440-41-7
History
DiscoveryLouis Nicolas Vauquelin (1797)
First isolationFriedrich Wöhler & Antoine Bussy (1828)
Main isotopes of bẹ́rílíọ̀mù
Iso­tope Abun­dance Half-life (t1/2) Decay mode Pro­duct
7Be trace 53.12 d ε 0.862 7Li
γ 0.477 -
9Be 100% 9Be is stable with 5 neutrons
10Be trace 1.36×106 y β 0.556 10B
Àdàkọ:Category-inline
| references

Itokasi

Tags:

Chemical elementMẹ́tàlì alkalínì ilẹ̀Nọ́mbà átọ̀mù

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

ỌdúnOṣù KẹtaH. H. AsquithWikiStephen Harper20 OctoberÈdè LárúbáwáWikinewsRachel BaardAtọ́ka Ìdàgbàsókè ÈnìyànRamesses VIIÌhìnrere LúkùOsorkonÀsà Ìgbéyàwó ní ilè YorùbáMuhammadu BuhariCopenhagenÀgbáyéÌṣíròDavid OyedepoOrílẹ̀-èdè Olómìnira Òṣèlú ilẹ̀ KóngòErékùṣùSikiru Ayinde BarristerMọ́skòỌbaÀtòjọ àwọn àjọ̀dúnTsẹ́kì OlómìniraÀmì ọ̀pá àṣẹ ilẹ̀ Nọ́rwèyỌ̀rànmíyànGbólóhùn YorùbáAyò ọlọ́pọ́nÀjákálẹ̀ àrùn káàkiriayé èrànkòrónà ọdún 2019 2020OklahomaKylian Mbappé22 JuneSenior Advocate of NigeriaFlorence Griffith-JoynerVincent van GoghISO 8601FacebookPúẹ́rtò RíkòGbogbo Ìpawó Orílẹ̀-èdèIrinEmperor Shōmu26 SeptemberPeter FatomilolaEmperor Meiji26 MayÌpínlẹ̀ ÈkóPorto NovoÌgèElihu RootPópù Alexander 2kÒrìṣà EgúngúnÌjímèrèTirana633 ZelimaAndré Frédéric CournandÀwọn sáyẹ́nsì àwùjọDaisy DucatiRita DominicIkọ́🡆 More