Arsenal F. C.

Arsenal Football Club jẹ́ ikọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá ṣiṣẹ́ tí ó fìkàlẹ̀ sí ìlú Islington ni London lorílẹ̀ èdè Gẹ̀ẹ́sì, tí ó ń díje nínú Ìdíje Àgbábuta Bọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá tí orílẹ̀ èdè Gẹ̀ẹ́sì, ìdíje Bọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá tí ó ga jùlọ lorílẹ̀ èdè Gẹ̀ẹ́sì.

Ikọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá yìí tí gba ìfẹ́-ẹ̀yẹ mẹ́tàlá nínú Ìdíje Àgbábuta Bọ́ọ̀lù-Àfẹsẹ̀gbá tí orílẹ̀ èdè Gẹ̀ẹ́sì, bẹ́ẹ̀ náà ni ó gba ife ẹ̀yẹ FA Cup mẹ́tàlá àti àwọn àṣeyọrí mìíràn nínú ìdíje Bọ́ọ̀lù Àfẹsẹ̀gbá. Arsenal F. C. jẹ́ ikọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá àkọ́kọ́ láti apá gúúsù orílẹ̀ èdè Gẹ̀ẹ́sì láti darapọ̀ mọ́ Ìdíje Àgbábuta Bọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá tí orílẹ̀ èdè Gẹ̀ẹ́sì lọ́dún 1893, wọn sìn tún jẹ́ ipò kejì nínú àwọn ikọ̀ tó pegedé jùlọ nínú àwọn ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá jẹun lórílẹ̀ èdè Gẹ̀ẹ́sì. Lọ́dún 1930 àti jù bẹ́ẹ̀ lọ, Arsenal F. C. gba ife ẹ̀yẹ márùn-ún, àti àwọn ife ẹ̀yẹ mìíràn tó tó márùn-ún. Lẹ́yìn náà, ọ̀pọ̀lọpọ̀ ife ẹ̀yẹ, pàápàá jù lọ Ìdíje Àgbábuta Bọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá tí orílẹ̀ èdè Gẹ̀ẹ́sì.

Arsenal
Arsenal F. C.
Full nameArsenal Football Club
Nickname(s)The Gunners
FoundedOṣù Kẹ̀wá 1886; ọdún 137 sẹ́yìn (1886-10) as Dial Square
GroundEmirates Stadium
(Capacity: 60,704)
OwnerKroenke Sports & Entertainment
ChairmanSir Chips Keswick
Head coachMikel Arteta
LeagueÀdàkọ:English football updater
Àdàkọ:English football updaterÀdàkọ:English football updater
WebsiteClub home page
Arsenal F. C.
Team colours
Arsenal F. C.
Team colours
Arsenal F. C.
Team colours
Arsenal F. C.
Team colours
Arsenal F. C.
Team colours
Home colours
Arsenal F. C.
Team colours
Arsenal F. C.
Team colours
Arsenal F. C.
Team colours
Arsenal F. C.
Team colours
Arsenal F. C.
Team colours
Away colours
Arsenal F. C.
Team colours
Arsenal F. C.
Team colours
Arsenal F. C.
Team colours
Arsenal F. C.
Team colours
Arsenal F. C.
Team colours
Third colours
Arsenal F. C. Current season

Àwọn Ìtọ́kasí

Tags:

Ìdíje Àgbábuta Bọ́ọ̀lù-Àfẹsẹ̀gbá tí orílẹ̀ èdè Gẹ̀ẹ́sì

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Ngozi OparaOsorkonÀlọ́ÌgbéyàwóC++John Carew EcclesOrílẹ̀ èdè AmericaJohn LewisLẹ́tà gbẹ̀fẹ̀ÌnàkíOṣù Kínní 10Lẹ́tà Àìgbẹ̀fẹ̀Adenike OlawuyiOṣù KejeIléKòkòròMohamed ElBaradeiLogicElisabeti KejìAlfred NobelÀgbáyéNaijiriaÀsìkòMọfọ́lọ́jì èdè YorùbáÌbálòpọ̀Alifabeeti Oduduwa6 February31 JulyFẹlá KútìMurtala MuhammadTuedon MorganAntárktìkìYorùbáPythagorasẸkún ÌyàwóMọ́remí Ájàṣorozoe29SaworoideVictoria UmunnaOsmiumRadon306 UnitasNọ́mbà àkọ́kọ́MichiganOṣù KẹfàLouis 13k ilẹ̀ FránsìEukaryaÒrò àyálò YorùbáOkoẹrúEukaryote(5813) 1988 VLKuala LumpurPópù Stephen 9kFloridaKúbà8 NovemberÌran YorùbáElihu RootBoriPornhubOrúkọ Yorùbá8 May🡆 More