Ìdarapọ̀mọ́ra Kẹ́míkà

Idarapomora kemika je igbese to n fa iyipada akojopo ohun kemika si omiran.

Awon idarapomora kemika je ohun ti awon onimo kemistri nko ninu papa sayensi to n je kemistri. Awon idarapomora kemika le je lojiji, ti ko fe okun/agbara kankan, tabi alaije lojiji, to le sele leyin igbati a ba se afikun iru okun/agbara kan sibe, fun apere igbona, imole tabi itanna. Awon idarapomora kemika je awon iyipada to je mo irin awon elektroni lati da tabi tuka awon isorapo kemika, botilejepe itumo gbogbogbo idarapomora kemika, agaga bo se je ti isodogba kemika, wulo fun iyipada awon elementary particles, ati fun awon idarapomora tinuatomu.

Ìdarapọ̀mọ́ra Kẹ́míkà
Oru omi Haidrojini oniklorini ninu igo ati ammonia ninu igo idanwo pade lati da isu ohun tuntun, amoniomu oniklorini

Ohun/awon ohun to bere idarapomora kemika ni a npe ni awon oludarapomora. Idarapomora kemika nfa iyipada kemika wa, eyi le mu eso kan tabi pupo wa, ti ohun ini won yato si ti awon oludarapomora.



Itokasi

Tags:

Chemical bondChemical substanceChemistryElectricityElectron

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

LeadYorùbáMọ́remí ÁjàṣoroÀjákálẹ̀ àrùn káàkiriayé èrànkòrónà ọdún 2019 2020Orílẹ̀-èdè31 DecemberFránsì12 FebruaryAzareÀpàlà8 OctoberISBNInternet Movie DatabaseNapoleon BonaparteISO 13406-2Olórí ìjọbaÌlàoòrùn Jẹ́mánìISO 13490Kashim ShettimaNneka EzeigboOṣù KẹrinInternetÀwọn Ẹ̀ka-èdè YorùbáISO 8601LisbonAnatole FranceMackenzie Bowell6 MayÈdè GermanyÌgbà SílúríàỌyaHTMLMariam CoulibalyDVỌjọ́ ÀìkúLítíréṣọ̀Ọ̀rúnmìlà1168 BrandiaPópù Jòhánù Páúlù ÈkejìÀsà Ìgbéyàwó ní ilè Yorùbá26 MaySamuel Ajayi CrowtherNigerian People's PartyAdekunle GoldNẹ́dálándìqi31gEuropeNikita KhrushchevTsẹ́kì OlómìniraEnglish languageÀdánidáTenzin Gyatso, 14th Dalai LamaBárbádọ̀sBD MimọSebastián PiñeraOperating SystemKàlẹ́ndà GregoryÀkúrẹ́Mohamed ElBaradeiMike EzuruonyeZheng HeNadia Fares AnlikerMarcel ProustÀsìkòEmperor ShōmuÀwọn Ọba Ilẹ̀ Yorùbá🡆 More