Ìdìbòyàn

Ìdìbò jẹ́ ìpinnu àti ìgbésẹ tí àwọn ènìyàn kan gbà láti yan ẹni tí yóò ṣojú tàbí darí wọn sípò.

Ìdìbòyàn
Ọwọ́ tó ń dìbò.

Ìdìbò ti jẹ́ èròjà ìṣèjọba àwaarawa láti bíi sẹ́ńtúrì mẹ́tàdínlógún sẹ́yìn. A máà ń lò ó fún yíyan ni sípò aṣòfin àti ti aṣojúṣòfin àti sí Ìjọba ìbílẹ̀ pẹlú ti ẹlẹ́kùnjẹkùn. Ìgbésẹ yìí tún wọpọ ní àwọn Ilé-iṣẹ́ ńlá-ńlá àti ti aládani pẹlú àwọn ẹlẹ́gbẹ́jẹgbẹ́.

Ìlo káríayé ìdìbò gégé bí èròjà fún yíyan asojú tí ó wọpọ ní ìjọba àwaarawa ti àsìkò yìí wà ní ìyàtọ̀ sí ti ayé àtijọ́ nigbati yíyan ni sípò máa ń wáyé nípa lílosortition,Ẹni orí yàn tabi kádàrá nípa ṣíṣe èyí-jẹ-èyí-o-jẹ láti fi yàn wọ́n sípò.

Àtúnṣe sí ètò ìdìbò ṣe àfihàn àwọn ìgbésẹ tí wọ́n ń se fun ìrọwọ́-ìrọsẹ̀ nínú ètò ìdìbò tàbí síṣe àtúnṣe sí àwọn ètò ìdìbò tí ó wà nílẹ̀ tẹ́lẹ̀. PsephologySífọ́lọ́jì jẹ́ ẹ̀kọ́ nípa èsì ìdìbò àti àwọn ìṣirò mìíràn tí ó rọ̀mọ́ ètò ìdìbò ní pàtàkì jùlọ láti ṣírò èsì ìdìbò náà síwájú kíkéde rẹ̀. Ìdìbò jẹ kókó dídìbòyàn tàbí ìdìbòyan

Láti "dìbò" túmọ sí láti Yàn tàbí ṣe "ìpinnu" àti nígbà mìíràn,wọn máa ń lo àwọn ìwé pélébé aláfọwọ́jù sínú àpótí gégébí ìdìbò(referendum).Ìlú Amẹ́ríkà ní èyí tí wọ́pọ̀ jùlọ.

Itokasi

Tags:

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

George Clinton (Igbákejì Ààrẹ)DNAEhoroLizzy jay21 OctoberÌran YorùbáKuala LumpurỌ̀rọ̀-Orúkọ (Èdè Yorùbá)(6840) 1995 WW5Adó-ÈkìtìPolinésíàSan FranciscoAfghanístànÀwọn èdè Índíà-EuropeVladimir Putin3 NovemberÒmìnira28 SeptemberAsaba, NàìjíríàKòkòrò17 OctoberAlfred NobelÌhìnrere LúkùEre idarayaIodineSune BergströmSàmóà Amẹ́ríkàOlúṣẹ́gun Ọbásanjọ́234 Barbara22 JuneFúnmiláyọ̀ Ransome-KútìÒgún LákáayéMary AkorIranian rial26 JuneẸrankoẸyẹ1 NovemberAustrálíàRepublican Party (United States)ISO 3166-3Florida10 AprilÌlàoòrùn Jẹ́mánìỌyaOmiErékùṣùÈdè GermanyAlifabeeti OduduwaMaria NajjumaLẹ́tà Àìgbẹ̀fẹ̀Ìtàn àkọọ́lẹ̀ YorùbáArgonPsamtik 1kSenior Advocate of NigeriaÌpínlẹ̀ ÒgùnCoat of arms of South KoreaÀrún èrànkòrónà ọdún 201929 AugustBratislavaFIFAOgun Àgbáyé Ẹlẹ́ẹ̀kejìTógòOsmium🡆 More