Ògógóró

Ògógóró jẹ́ ọtí líle ìbílẹ̀ tí wọ́n pọn láti ara ẹmu igi ọ̀pẹ tàbí agbe.

Ó jẹ́ ọtí líle ìbílẹ̀ tí wọ́n máa ń mú káàkiri ìwọ̀-oòrùn Áfíríkà, pàápàá jùlọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. . Lóde òní, ọ̀pọ̀ èèyàn ló máa ń ka ethanol sí ògógóró, ṣùgbọ́n èyí kò rí bẹ́ẹ̀ rárá. Kẹ́míkà ni ethanol, ṣùgbọ́n ògógóró jẹ́ ọtí líle ìbílẹ̀ tí wọ́n pọn láti ara ẹmu igi ọ̀pẹ tàbí agbe.

Àwọn orúkọ mìíràn tí wọ́n ń pe ògógóró

Akpeteshie lórílẹ̀ èdè Ghana, Omi sapele, pàrágà, kain-kain, Sùn gbalaja, éégún inú ìgò, jẹ́ díè lára àwọn onírúurú orúkọ tí àwọn ènìyàn máa ń pe ògógóró káàkiri ilẹ̀ Yorùbá àti Áfíríkà. Àwọn orúkọ mìíràn tí onírúurú àwọn ènìyàn tún máa ń pè é ní ufofopCalabar, rọ́birọ́biAbẹ́òkúta, baba erin Iléṣà, òyìnbó gọ̀, majidun, etonto lédè Àdàmọ̀dì Gẹ̀ẹ́sì, wuru, àwọn Ijaw, Udi Ogagan àti Àdàkọ:Not a typo Bini, Agbagba Urhobo,àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.

Àwọn Ìtọ́kasí

Tags:

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Osama bin LadenZagrebChristmasÌrìnkánkán àwọn Ẹ̀tọ́ Aráàlú ọmọ Áfríkà Amẹ́ríkà (1955–1968)Ajọfọ̀nàkò Àsìkò KáríayéEmilio AguinaldoCreative CommonsCaliforniaÀmìọ̀rọ̀ ANSI escapeMaltaISO 3103Ìsọ̀kan Sófìẹ̀tìAgbonISO 639-3OpenDocumentWúràBimbo AdemoyeISO 3166-1Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣunNeil ArmstrongInstagramCurtis MayfieldJẹ́ọ́gráfìFemi GbajabiamilaEre idarayaPópù Benedict 1kPọ́nnaJosé de la Riva Agüero594 MireilleUsain BoltUzbekistanSlovakiaSani AbachaỌba ìlú ÈkóAberdeenWikimediaOlóṣèlúDavid Samanez OcampoBoolu-afesegbaAlexander HamiltonPalẹstínìISO 5776Sammy Davis, Jr.Masẹdóníà ÀríwáEpoÀwọn ìṣẹ̀lẹ̀ ìdánilóró September 11, 2001.auISO/IEC 144432120 TyumeniaAstanaÀkàyéÀsà ilà kíkọ ní ilé YorùbáRosa LuxemburgISO 6523AcehPornhubÍsráẹ́lìSonyÀwọn Ìpínlẹ̀ Aṣọ̀kan ilẹ̀ Amẹ́ríkàFaithia BalogunOgedengbe of Ilesa🡆 More