Curtis Lee Mayfield (June 3, 1942 – December 26, 1999) je omo orile-ede Amerika akorin ati atokun soul, rhythm and blues, ati funk, ohun lo se atokun ati akorin fun filmu Super Fly.
Nitori bi ise orin bayi o je gbigba gege bi asiwaju ninu orin Funk ati awon orin awon ara Afrika Amerika to je mo toloselu.
Curtis Mayfield | |
---|---|
Background information | |
Orúkọ àbísọ | Curtis Lee Mayfield |
Irú orin | Soul, rhythm and blues, funk, Chicago soul, psychedelic soul |
Occupation(s) | singer-songwriter, record producer, multi-instrumentalist |
Instruments | vocals, guitar, bass, piano, saxophone, drums |
Years active | 1958–1999 |
Labels | Curtom, Warner Bros., Rhino |
Associated acts | The Impressions, Jerry Butler |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Curtis Mayfield, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.