René Descartes

René Descartes (ìpè Faransé: ​; 31 March 1596 – 11 February 1650) (Kiko ni Latin: Renatus Cartesius; oro aponle: Kartesi tabi Cartesian ni geesi), je amoye ara Fransi, onimo mathimatiki, onimo fisksi, ati olukowe to gbe opo igbesiaye agbalagba re ni orile-ede Hollandi Olominira.

Won ti pe ni bi "Baba Imoye Odeoni", beesini opo Imooye apaiwoorun je bi esi si awon iwe to ko, ti won si tun unje gbigbeka momomo doni. Agaga, iwe re Meditations on First Philosophy si je doni iwe pataki ni awon ipin-apa imoye ni awon yunifasiti. Ipa Descartes ninu mathimatiki han kedere; ohun lo seda sistemu ajofonako Kartesi—ungba irisi jeometri laaye lati je gbigbekale ni isedogba aljebra. Ohun lo je sisawin bi baba jeometri alatuwo. Descartes na tun je ikan ninu awon to se bere Ijidide Sayensi.

René Descartes
Rene Dekart
René Descartes
Portrait after Frans Hals, 1648.
OrúkọRené Descartes
Rene Dekart
Ìbí(1596-03-31)Oṣù Kẹta 31, 1596
La Haye en Touraine (titunso di Descartes), Indre-et-Loire, Fransi
AláìsíFebruary 11, 1650(1650-02-11) (ọmọ ọdún 53)
Stockholm, Swidin
ÌgbàÌmòye ọrúndún 17th
AgbègbèÌmòye Apáìwọ̀orùn
Ẹ̀ka-ẹ̀kọ́Cartesianism, Rationalism, Foundationalism
Ìjẹlógún ganganMetaphysics, Epistemology, Science, Mathematics
Àròwá pàtàkìCogito ergo sum, method of doubt, Cartesian coordinate system, Cartesian dualism, ontological argument for the existence of God; regarded as a founder of Modern philosophy
Ìtọwọ́bọ̀wéRené Descartes

Itokasi


Tags:

en:Help:IPA/French

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

ÒjéTheodosius 1kMarsWokingMenkauhor KaiuAfghanístànÒrò àyálò YorùbáHTMLIlà kíkọ nílẹ̀ YorùbáIlẹ̀ Ọbalúayé RómùMẹ́tálọ́ìdìWilliam ShakespeareAustrálíàHelmut KohlFacebookNew York (Ìpínlẹ̀)Theodore RooseveltSt. George's, Grẹ̀nádàIPhonePópù Marcellus 2kVladimir PutinBudapestPanamaBelfastDomitianỌjọ́ Ìsẹ́gunHondurasDubaiPétérù Mímọ́WikipediaEuroÀtòjọ àwọn ẹlẹ́bùn Nobel nínú FísíksìAkọ ibàVirginia WadeDram ArméníàRodney Joseph JohnsonClevelandMichael JacksonNeferirkare KakaiAlbert EinsteinÌran YorùbáÀmì ọ̀pá àṣẹ ilẹ̀ MàkáùEugenio MontaleKigaliAli NuhuMichael CaineJẹ́mánì NaziÀwọn Ìdíje Òlímpíkì Ìgbà Oru 2012George MarshallVladimir LeninLọndọnuFrancisco FrancoRáràPataki oruko ninu ede YorubaMọ́remí ÁjàṣoroMadagásíkàYousaf Raza GillaniTsílèAderounmu AdejumokeDàmáskùYvonne NelsonJames WattTutankhamun67085 OppenheimerNomsebenzi TsotsobeNew YorkHenry JamesDresdenÈdè PólándìZimbabweIndianaÒgún LákáayéOrin Rhythm and bluesMuhammad Ali🡆 More