John Locke (pípè /ˈlɒk/; 29 Osu Kejo 1632 – 28 Osu Kewa 1704), to gbajumo gege bi Baba Isealainide, je amoye ati onisegun ara Ilegeesi to je ikan larin awon onironu Olaju to ni ipa julo.
Won gba bi ikan lara awon aseoniriri akoko ara Britani, nipa titele asa ti Francis Bacon bere, bakanna o tun se pataki si ero adehun awujo. Ise re se pataki fun idagbasoke epistemology ati imoye oselu. Awon iwe re ni ipa lori Voltaire ati Rousseau, opo awon onironu Olaju Skotlandi, ati bakanna lori awon Olujidide Amerika. Ipa re si iseolominira ijohun ati ero alainide han ninu Ifilole Ilominira Amerika .
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article John Locke, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.