Owó-Ẹ̀yìn

Owó-ẹ̀yìn tàbí Ẹ̀gúnjẹ ni gbígba owó tàbí ẹ̀bùn mìíràn lọ́nà àìtó láti ṣẹ̀gbẹ̀ fúnni fún èyíkéyìí àǹfàní.

Ó jẹ́ ọ̀kan lára ìwà àjẹbánu tó burú jáì. Àwọn ọ̀gá ilé-iṣẹ́, àwọn olórí, Aláṣẹ tàbí àwọn olóṣèlú ni aje ìwà ìbàjẹ́ yìí sáàbà máa ń sẹ́ lórí jùlọ. Àwọn àwọn Adájọ́, Ọ̀lọ́pàá àti àwọn agbófinró mìíràn a máa gba Ẹ̀gúnjẹ láti ṣẹ̀gbẹ̀ fún ọ̀daràn tàbí láti gbẹ́bi fún aláre. Owó-ẹ̀yìn, tí a tún lè pè ní owó-àbẹ̀tẹ́lẹ̀ tún máa ń wáyé àwọn ilé ẹ̀kọ́. Àwọn olùkọ́ mìíràn a máa Ẹ̀gúnjẹ láti fún akẹ́kọ̀ọ́ ní máàkì tàbí fún un ní èsì ìbéèrè ìdánwò.

Owó-Ẹ̀yìn
Giving money illegally or unethically to influence a person's behavior is a form of bribery.
Owó-Ẹ̀yìn

Àwọn Ìtọ́kasí


Tags:

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

ÌnáwóAisha AbdulraheemÌwé àwọn Onídàjọ́Rial OmaniPópù Alexander 2k1 NovemberÀdánidáOrúkọ ìdíléVictoria University of ManchesterÀpàlàInstagramÀṣà Ìsọmọ-lórúkọ nílẹ̀ YorùbáTurkmẹ́nìstánỌdẹÌyáStephen HarperTunisiaMartina NavratilovaSaint PetersburgBitcoinWikiMichiganItan Ijapa ati AjaAnatole FranceSÈdè FaranséBD MimọCheryl Chase (activist)Ìran YorùbáÀṣà Ìsọmọlórúkọ Nílẹ̀ YorùbáOṣù KejìláISO 8601KùwéìtìÍsráẹ́lì1229 TiliaAdenike OlawuyiRoland BurrisẸrankoEuropeAssamÈdè TàmilRichard Mofe DamijoÀmì ọ̀pá àṣẹ ilẹ̀ Nọ́rwèyPennsylvaniaWoodrow WilsonBrie LarsonGúúsù SudanMary SoronadiFESTAC 77John LewisLucie ŠafářováIrinMontanaWikipẹ́díà l'édè YorùbáÈdè GermanyOṣù KẹtaYttriumMarcel ProustAuguste Beernaert13 OctoberHilda BaciGíríìsìEukarya20634 MarichardsonChristian Bale25 March🡆 More