Májẹ̀mú Láéláé

Májẹ̀mú Láéláé je apa kinni ninu Bibeli Mimo, tí ó ní ìwé ọkàn dín logoji, tí wón kó ni èdè Hébérù.

Apá kejì Bíbélì mímọ́ ni májẹ̀mú tuntun, èyí tí a ko ni èdè Griki, tí ó sì jẹ́ àkójọ ìwé metadinlogbon.

Májẹ̀mú Láéláé
Àwòrán tó ń ṣàfihàn májẹ̀mú láéláé.

Májẹ̀mú láéláé jẹ́ akojopo orísi àwọn ìwé tí orisi àwọn ènìyàn mímọ́ ko ni ọpọlọpọ ọdún sẹ́yìn..

Àwọn Kristẹni pín majẹmu Láéláé sí merin: àkókò ni ìwé marun àkókò; àwọn ìwé tí ó sọ nípa ìtàn àwọn ọmọ Israeli, láti ìṣẹ́gun wọn ní Canani sí ìgbà tí a kọ Bábílónì lẹ́ru; àwọn ìwé ọgbọ́n àti ewì àti àwọn ìwé nípa àwọn wòlíì májẹ̀mú Láéláé.

Májẹ̀mú láéláé jẹ́ àkójọ ìwé ọkàn dín logoji, bí ó tilè jẹ́ wípé ìwé Májẹ̀mú Láéláé tí àwọn ìjọ míràn bí ìjọ Kátólíìkì ń lò ní ìwé tí ó tó merindinladota.

Itokasi

Tags:

Bibeli Mimo

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Gúúsù Amẹ́ríkàÌlú-ọba Brítánì OlókìkíMercedes-BenzKenneth Arrow.geHassiomuGoogleDavid BeckhamSudanAgbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ido-OsiÀwọn Bàhámà25 JulyISO 652318946 MassarÀsìá ilẹ̀ KánádàÌwọ́ ìtannáLéon BlumCarlos SoubletteISBNApágúúsù ÁfríkàAta ṣọ̀mbọ̀22 OctoberWiki Commons23 AugustItan ijapa ati igbin17 March6 AugustYemojaSérbíà àti MontenégròWaterGeorge ReadFrederick North, Lord NorthZangbetọBórọ̀nù4363 SergejFàdákàolómiEarthRenée ZellwegerLeonid KantorovichAnkaraAma Ata AidooÁrktìkìVictoria University of ManchesterRihannaAdrien BrodyBlu-ray DiscỌdẹSaxonyÌgbéyàwóPópù Jòhánù 14kUSA8 SeptemberLos AngelesSimidele AdeagboAnschlussOhioQasem SoleimaniInternetFrederick Lugard24 AprilÈdè Faransé2009C++Ronald Colman🡆 More