Jimoh Buraimoh

Olóyè Jimoh Buraimoh (jẹ́ ẹni tí a bí ní ọdún 1943, gẹ́gẹ́ bi Jimoh Adetunji Buraimoh ) jẹ́ olùyàwòran àti olórin Nàìjíríà .

Olóyè Buraimoh jẹ ọ̀kan nínú àwọn Òṣèré tí ó ní ipa jùlọ láti jáde lati àwọn ìdánilẹ́kọ̀ọ́ ti ọdún 1960 ti Ulli Beier àti Georgina Beier ní Osogbo, Ìpínlẹ̀ Osun, Nigeria. Láti ìgbà náà, ó ti di ọ̀kan nínú àwọn Òṣèré olókìkí jùlọ tí ó wá láti Osogbo .


ÌBẸ̀RẸ̀ PẸ̀PẸ̀ AYÉ RẸ̀ ÀTI Ẹ̀KỌ́

ibẹrẹ ati ẹkọ

Jimoh Buraimoh ni a bÍ nÍ Osogbo, Ìpínlẹ̀ Osun, Nigeria, ní ọdún 1943 sínú ẹ̀ka ti Musulumi ti ìdílé ọba ti ìlú tí ó ti wá náà. Ó lọ sí àwọn ìdánilẹ́kọ̀ọ́ ti ọdún 1960 ti Ulli Beier ṣe, àti pé ó tún jẹ onímọ̀-ẹrọ ìtanná ni ilé ìṣèré Duro Ladipo .

Iṣẹ

Iṣẹ Jimoh Buraimoh dàpọ̀ mọ àwọn media ti ìlà oòrùn àti àwọn àṣà Yoruba . Wọ́n gbà pé ó jẹ́ ayàwòrán orí àkọ́kọ́ ní ilẹ̀ Áfíríkà nígbà tí ó ṣe ọ̀nà ọ̀nà ìgbàlódé kan tí ó ní ìmísí láti ara ọ̀dọ̀ àṣà Yorùbá láti ṣàkópọ̀ àwọn ọ̀nà ìlẹ̀kẹ̀ sínú àwọn aṣọ ayẹyẹ àti àwọn adé ìlẹ̀kẹ̀. Ni ọdún 1972, o ṣojú orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ni Ìfihàn ìṣòwò Gbogbo Áfíríkà àkọ́kọ́ ni ìlú Nairobi, Kenya . Ọ̀kan nínú àwọn àwòrán olókìkí rẹ ti gbé kalẹ ni World Festival of Black Arts, Festac '77 . Òun ni ọmọ Nàìjíríà àkọ́kọ́ tí wọ́n fún ní ẹ̀bùn ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ní ẹ̀ka ẹgbẹ́ àwọn oníṣẹ́ ọnà Mòsákì lágbàáyé.

Àwọn iṣẹ

Àwọn iṣẹ Jimoh Buraimoh ti ṣe àfihàn ní ilé àti ní òkèèrè.

Ẹ̀kọ́

Jimoh Buraimoh tun jẹ olorin ikọni daradara. Ni ọdun 1974, o kọ ẹ̀kọ́ ní Ile-iwe Haystack Mountain ti Àwọn iṣẹ ọnà ni Maine . Ó tún kọ ni University of Bloomington àti àwọn ilé-ìwé mìíràn ni New York, Boston àti Los Angeles.

Àwọn orísun àti àwọn ìtọ́kasí

Tags:

Jimoh Buraimoh ibẹrẹ ati ẹkọJimoh Buraimoh IṣẹJimoh Buraimoh Àwọn iṣẹJimoh Buraimoh Ẹ̀kọ́Jimoh Buraimoh Àwọn orísun àti àwọn ìtọ́kasíJimoh BuraimohOníṣọ̀nàUlli BeierÀwòrán kíkùnÌpínlẹ̀ Ọ̀ṣunÒṣogbo

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Nọ́mbà adọ́gba àti aṣẹ́kùVGeneral Exchange FormatKàsínòRichard PryorAtiku AbubakarGeorgiaAjodun odun BadagryHerbert C. BrownGuillermo Tell Villegas27 JulyAbdul-Azeez Olajide AdediranSouth African randHerbert MacaulayJacqueline WolperThe delivery boyZlatanIlẹ̀ Ọbalúayé Sọ́ngháìElizabeth BlackburnYunifásítì ìlú MàídúgùriNarendra ModiÀsìá ilẹ̀ Dẹ́nmárkìBennet OmaluÀwọn Ọba Ilẹ̀ YorùbáMicrolophus quadrivittatusRemi AdedejiSpéìnBola TinubuOwe YorubaBalboa12 NovemberFẹ́mi GbàjàbíàmílàUniversidade do Estado de Minas GeraisC++Rosalyn Sussman YalowAïcha BoroCasimir BetelEric Allin CornellFelix Abidemi FabunmiMike AdenugaJohn Lewis2023UNESCOÈdèe YorùbáDJ XclusiveDaniel O. FagunwaDavid BaltimoreLilian EsoroAdebukola OladipupoW.cySGalileo GalileiBenin pendant maskÀkójọ àwọn èdè iṣẹ́ọbaIlé-Ifẹ̀Nike OshinowoIkejaEuro27 SeptemberGuineaÌmúrìnRichard J. RobertsÀjọ tí ó ń mójú tó ońjẹ àti oògùn ti orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkàNeanderthalÀtòjọ Àwọn Ìwé-ìròyìn Lórílẹ̀-èdè Amẹ́ríkàKady TraoréÍsráẹ́lìMr MacaroniÀtọ̀sí ajáMayotteJ🡆 More