Galileo Galilei (Àdàkọ:IPA-it; 15 February 1564 – 8 January 1642) je ara Italia onimo fisiiki, mathematiiki, olutorawo, ati onimo oye to ko ipa pataki ninu Ijidide Sayensi.
Die ninu awon aseyori re ni atunse si teliskopu ati awon akiyesi irawo to se, ati itileyin ise Copernicus. Won ti pe Galileo ni "baba itorawo oniakiyesi odeoni," "baba fisiiki odeoni," the "baba sayensi," ati "Baba Sayensi Odeoni." Stephen Hawking so pe, "Galileo, ju elomiran, lo sise fun ibi sayensi odeoni."
Galileo Galilei | |
---|---|
Portrait of Galileo Galilei by Giusto Sustermans | |
Ìbí | Pisa, Duchy of Florence, Italy | 15 Oṣù Kejì 1564
Aláìsí | 8 January 1642 Arcetri, Grand Duchy of Tuscany, Italy | (ọmọ ọdún 77)
Ibùgbé | Grand Duchy of Tuscany, Italy |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Italian |
Pápá | Astronomy, Physics and Mathematics |
Ilé-ẹ̀kọ́ | University of Pisa University of Padua |
Ibi ẹ̀kọ́ | University of Pisa |
Academic advisors | Ostilio Ricci |
Notable students | Benedetto Castelli Mario Guiducci Vincenzio Viviani |
Ó gbajúmọ̀ fún | Kinematics Dynamics Telescopic observational astronomy Heliocentrism |
Religious stance | Roman Catholic |
Signature | |
Notes His father was the musician Vincenzo Galilei. His mistress was Marina Gamba and Maria Celeste was one of Galileo's daughters. |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Galileo Galilei, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.