Áfríkà: Orílè

Áfríkà ni orile keji titobijulo ati toni awon eniyan julo lagbaye leyin Asia.

Ni bi 30.2 egbegberun km² (11.7 million sq mi) lapapo mo awon erekusu to sunmo, ile re je 6% apapo gbogbo oju Aye ati 20.4% gbogbo ile Aye. Pelu egbegberunkeji kan eniyan (ni 2009, e wo tabili) ni awon agbegbe 61, eyi je bi 14.72% gbogbo iye eniyan Agbaye. Ni ariwa re ni Okun Mediterraneani wa, si ariwailaorun re ni Ilaodo Suez ati Okun Pupa wa legbe Sinai Peninsula, si guusuilaorun re ni Okun India, ati si iwoorun re ni Okun Atlantiki wa. Afrika ni orile-ede 54 lapapo mo Madagascar, opolopo erekusu ati orile-ede Olominira Sahrawi Arabu Toseluaralu, to je omo egbe Isokan Afrika botilejepe Morocco lodi si eyi.

Áfríkà
Áfríkà: Orisun itumo oro, Itan, Awon agbegbe
Ààlà30,221,532 km2 (11,668,598.7 sq mi)
Olùgbé1,000,010,000 (2005, 2nd)
Ìṣúpọ̀ olùgbé30.51 km2 (about 80/sq mi)
DemonymAfrican
Àwọn orílẹ̀-èdè53 (List of countries)
Dependencies
Àwọn èdèList of languages
Time ZonesUTC-1 to UTC+4
Àwọn ìlú tótóbijùlọList of cities

Afrika, agaga gbongan apailaorun Afrika, je gbigba lopolopo latowo awon awujo onisayensi pe ibe ni ibi ti awon eniyan ti bere ati Hominidae clade (great apes), gege bi o se han pelu iwari awon hominids pipejulo ati awon babanla won, ati awon ti won wa leyin won ti won peju bi odun legbegberun meje seyin – lapapomo Sahelanthropus tchadensis, Australopithecus africanus, A. afarensis, Homo erectus, H. habilis and H. ergaster – pelu eyi to pejulo ninu won Homo sapiens (eniyan odeoni) ti o je wiwari ni Ethiopia to je odun bi 200,000 seyin.

Afrika bo ibugedemeji mole, o si ni orisirisi awon agbegbe ojuojo; o je orile kan soso to gun lati agbegbe apaariwa aloworo de apaguusu alaworo.

Orisun itumo oro

Afri ni oruko awon eniyan ti won gbe ni Ariwa Afrika leba Carthage. Oruko awon wonyi je siso mo "afar" ti awon Finiki, to tumosi "eruku", sugbon ero 1981 kan ti so pe o wa lati oro ede Berber ifri tabi Ifran totumosi "cave", in reference to cave dwellers. Afrika tabi Ifri tabi Afer ni oruko Banu Ifran lati Algeria ati Tripolitania (Eya Berber ti Yafran).

Labe ijoba awon Ara Romu, Carthage di oluilu Igberiko Afrika, to tun je kikomo apa eba odo Libya oni. "-ka" ("ca") to je ilemeyin Afrika je awon Ara Romu to tokasi "orile-ede tabi ile". Bakanna, ile-oba Musulumi ayeijoun Ifriqiya to wa leyin, ti a mo loni bi Tunisia, na tun lo iru oruko yi.

Awon orisun itumo miran ti won ti da laba bi orisun oruko ijoun "Afrika":

  • omo Ju olukoitan ni orundun 1st Flavius Josephus (Ant. 1.15) so pe o je sisoloruko fun Epher, omokunrin omoomo Abraham gege bi Gen. 25:4, ti awon omomo re, bo se so, pe won bori Libya.
  • oro Latin aprica ("ihan orun"; "sunny") ti Isidore of Seville menu ba ninu Etymologiae XIV.5.2.
  • oro Griiki aphrike (Αφρική), to tumosi "aini otutu." Olukoitan Leo Africanus (1488–1554) lo damoran yi, to daba oro Griiki phrike (φρίκη, to tumosi "otutu ati eru"), lapapo mo "a-", lati tumosi "ile ti ko ni otutu ati eru.
  • Massey, ni 1881, mu orisun itumo kan wa lati oro Egypti af-rui-ka, "di dori ko ojuona Ka." Ka tokasi ibiomo. Nipa eyi Afrika je fun awon Ara Egypti, "ile ibimo."

Itan

Itan atijo

Ni ibere Igba Mesosoik, Afrika je jijapo mo awon orile Aye yioku gege bi Pangea. Afrika pin awon fauna kanna ti orilegbangba yi ti o je sisori lowo awon theropods, prosauropods ati ornithischians akokolo nigbati igba Trias wa sopin. Awon idokuta opin je wiwari kakiri Africa, sugbon won wopo ni guusu ju ariwa lo. Ila to ya igba Triassic soto si Jurassic lo falasi ibere awon isele iparun to ni ip ni lagbaye, botilejepe strata Afrika igba yi ko ti je gbigbewo daada.

Awon ipele ile igba Ibere Jurassik pinkiri lona kanna bi ti isun Late Triassic, with more common outcrops in the south and less common fossil beds which are predominated by tracks to the north. As the Jurassic proceeded, larger and more iconic groups of dinosaurs like sauropods and ornithopods proliferated in Africa. Middle Jurassic strata are neither well represented nor well studied in Africa. Late Jurassic strata are also poorly represented apart from the spectacular Tendaguru fauna in Tanzania. The Late Jurassic life of Tendaguru is very similar to that found in western North America's Morrison Formation.

Orundun 9k–18k

Afrika ki o to di ibialamusin o se e se ki o ni orisirisi orile-ede otooto to ju 10,000 lo ati asejoba to ni orisirisi ilana ati agbajo oloselu. Ninu awon wonyi ni idipo ebi kekere awon asode bi awon San ni apaguusu Afrika; titobi, awon adipo adimule bi awon idipo ibatan ebi awon elede Bantu ni apaarin ati apaguusu Afrika, awon adipo ibatan adimule gidigidi ni Ibi Iwo Ori Afrika, awon ileoba Saheli titobi, ati awon ilu-orilejoba ati awon ileoba aladawa bi ti awon Yoruba ni Iwoorun Afrika, ati awon ilu oja etiodo awon Swahili ni Ilaorun Afrika.

Nigba to fi di orundun 9k SK orisirisi awon orilejoba obairanderan, ti awon orilejoba Hausa akoko wa ninu won, ti san kakiri saffana abe-sahara lati awon agbegbe apaiwoorun de ibiarin Sudan. Awon to lagbarajulo larin awon orilejoba wonyi ni Ghana, Gao, ati Kanem-Bornu Empire. Agbara Ghana dinku ni orundun 11k sugbon Ileobaluaye Mali ropo re, eyi lo si di opo gbogbo apaiwoorun Afrika mu ni orundun 13k. Kanem gba esin Imale ni orundun 11k. Be sini ni awon agbegbe igbo etiodo Iwoorun Afrika, awon ileoba alominira jadide laini ipa kankan latodo ariwa Musulumi.


Áfríkà: Orisun itumo oro, Itan, Awon agbegbe 
Ashanti yam ceremony, 19th century by Thomas E. Bowdich

Ife, to je akoko larin awon ilu-orilejoba tabi ileoba Yoruba, sedasile ijoba labe oba, ton unje Ooni. Ife je ibi pataki esin ati asa ni Afrika, ati fun asa ibile ere gbigbe. Iru ifijuwe ijoba Ile-Ife je gbigbamulo ni Oyo, nibiti awon oba, ti won unje Alaafin ti figba kan joba lori opo iye iluorilejoba ati ileoba Yoruba miran ati ti awon ti won ko je Yoruba, Ileoba Dahomey awon Fon je ibi ti won ko so ede Yoruba labe ijoba Oyo.


Awon Almoraffidi, je obairanderan Beriberi lati Sahara ti won fon kiri ariwaapaiwoorun Afrika ati peninsula Iberian nigba orundun 11k. Banu Hilal ati Banu Ma'qil je akopo aon eya Arab Bedouin lati Arabian peninsula ti on kolo si iwoorun lati Egypt larin orundun 11k ati 13k. Ikoreokere fa idapo awon Arabu ati Beriberi, nibi ti awon ara ile ti di Arabu, be sini asa Arabu gba apilese asa ibile ibe, labe isokan Islam.

Awon agbegbe

Àwọn orílẹ̀-èdè tí wọ́n wà ní ìpele yí ni wọ́n wà lábẹ́ àtò scheme for geographic subregions tí àjọ United Nations, àti data tí ó rọ̀ mọ́ ìtọ́ka sí fún àpilẹ̀kọ. Where they differ, provisos are clearly indicated.

Áfríkà: Orisun itumo oro, Itan, Awon agbegbe 
Regions of Africa:
 
 
Áfríkà: Orisun itumo oro, Itan, Awon agbegbe 
Physical map of Africa
Áfríkà: Orisun itumo oro, Itan, Awon agbegbe 
Satellite photo of Africa
Áfríkà: Orisun itumo oro, Itan, Awon agbegbe 
Political map of Africa
Orúkọ agbègbè àti
ilẹ̀, pẹ̀lú asìá
Ààlà
(km²)
Alábùgbé
(2009 est) except where noted
Ìṣúpọ̀
(per km²)
Olúìlú
Eastern Africa: 6,384,904 316,053,651 49.5
Áfríkà: Orisun itumo oro, Itan, Awon agbegbe  Burundi 27,830 8,988,091 322.9 Bujumbura
Áfríkà: Orisun itumo oro, Itan, Awon agbegbe  Comoros 2,170 752,438 346.7 Moroni
Áfríkà: Orisun itumo oro, Itan, Awon agbegbe  Djibouti 23,000 516,055 22.4 Djibouti
Áfríkà: Orisun itumo oro, Itan, Awon agbegbe  Eritrea 121,320 5,647,168 46.5 Asmara
Áfríkà: Orisun itumo oro, Itan, Awon agbegbe  Ethiopia 1,127,127 85,237,338 75.6 Addis Ababa
Áfríkà: Orisun itumo oro, Itan, Awon agbegbe  Kenya 582,650 39,002,772 66.0 Nairobi
Áfríkà: Orisun itumo oro, Itan, Awon agbegbe  Madagascar 587,040 20,653,556 35.1 Antananarivo
Áfríkà: Orisun itumo oro, Itan, Awon agbegbe  Malawi 118,480 14,268,711 120.4 Lilongwe
Áfríkà: Orisun itumo oro, Itan, Awon agbegbe  Mauritius 2,040 1,284,264 629.5 Port Louis
Áfríkà: Orisun itumo oro, Itan, Awon agbegbe  Mayotte (France) 374 223,765 489.7 Mamoudzou
Áfríkà: Orisun itumo oro, Itan, Awon agbegbe  Mozambique 801,590 21,669,278 27.0 Maputo
Áfríkà: Orisun itumo oro, Itan, Awon agbegbe  Réunion (France) 2,512 743,981(2002) 296.2 Saint-Denis
Áfríkà: Orisun itumo oro, Itan, Awon agbegbe 
Rwanda 
26,338 10,473,282 397.6 Kigali
Áfríkà: Orisun itumo oro, Itan, Awon agbegbe  Seychelles 455 87,476 192.2 Victoria
Áfríkà: Orisun itumo oro, Itan, Awon agbegbe  Somalia 637,657 9,832,017 15.4 Mogadishu
Áfríkà: Orisun itumo oro, Itan, Awon agbegbe  Tanzania 945,087 41,048,532 43.3 Dodoma
Áfríkà: Orisun itumo oro, Itan, Awon agbegbe 
Uganda 
236,040 32,369,558 137.1 Kampala
Áfríkà: Orisun itumo oro, Itan, Awon agbegbe  Zambia 752,614 11,862,740 15.7 Lusaka
Middle Africa: 6,613,253 121,585,754 18.4
Áfríkà: Orisun itumo oro, Itan, Awon agbegbe  Angola 1,246,700 12,799,293 10.3 Luanda
Áfríkà: Orisun itumo oro, Itan, Awon agbegbe  Cameroon 475,440 18,879,301 39.7 Yaoundé
Áfríkà: Orisun itumo oro, Itan, Awon agbegbe  Central African Republic 622,984 4,511,488 7.2 Bangui
Áfríkà: Orisun itumo oro, Itan, Awon agbegbe  Chad 1,284,000 10,329,208 8.0 N'Djamena
Áfríkà: Orisun itumo oro, Itan, Awon agbegbe  Congo 342,000 4,012,809 11.7 Brazzaville
Áfríkà: Orisun itumo oro, Itan, Awon agbegbe 
Democratic Republic of the Congo 
2,345,410 68,692,542 29.2 Kinshasa
Áfríkà: Orisun itumo oro, Itan, Awon agbegbe  Equatorial Guinea 28,051 633,441 22.6 Malabo
Áfríkà: Orisun itumo oro, Itan, Awon agbegbe  Gabon 267,667 1,514,993 5.6 Libreville
Áfríkà: Orisun itumo oro, Itan, Awon agbegbe  São Tomé and Príncipe 1,001 212,679 212.4 São Tomé
Northern Africa: 8,533,021 211,087,622 24.7
Áfríkà: Orisun itumo oro, Itan, Awon agbegbe  Algeria 2,381,740 34,178,188 14.3 Algiers
Áfríkà: Orisun itumo oro, Itan, Awon agbegbe  Egypt 1,001,450 83,082,869 total, Asia 1.4m 82.9 Cairo
Áfríkà: Orisun itumo oro, Itan, Awon agbegbe  Libya 1,759,540 6,310,434 3.6 Tripoli
Áfríkà: Orisun itumo oro, Itan, Awon agbegbe  Morocco 446,550 34,859,364 78.0 Rabat
Áfríkà: Orisun itumo oro, Itan, Awon agbegbe 
Sudan 
2,505,810 41,087,825 16.4 Khartoum
Áfríkà: Orisun itumo oro, Itan, Awon agbegbe  Tunisia 163,610 10,486,339 64.1 Tunis
Áfríkà: Orisun itumo oro, Itan, Awon agbegbe  Sahrawi Arab Democratic Republic 266,000 405,210 1.5 El Aaiún
Spanish and Portuguese territories in Northern Africa:
Áfríkà: Orisun itumo oro, Itan, Awon agbegbe  Canary Islands (Spain) 7,492 1,694,477(2001) 226.2 Las Palmas de Gran Canaria,
Santa Cruz de Tenerife
Áfríkà: Orisun itumo oro, Itan, Awon agbegbe  Ceuta (Spain) 20 71,505(2001) 3,575.2
Áfríkà: Orisun itumo oro, Itan, Awon agbegbe  Madeira Islands (Portugal) 797 245,000(2001) 307.4 Funchal
Áfríkà: Orisun itumo oro, Itan, Awon agbegbe  Melilla (Spain) 12 66,411(2001) 5,534.2
Southern Africa: 2,693,418 56,406,762 20.9
Áfríkà: Orisun itumo oro, Itan, Awon agbegbe  Botswana 600,370 1,990,876 3.3 Gaborone
Áfríkà: Orisun itumo oro, Itan, Awon agbegbe 
Lesotho 
30,355 2,130,819 70.2 Maseru
Áfríkà: Orisun itumo oro, Itan, Awon agbegbe  Zimbabwe 390,580 11,392,629 29.1 Harare
Áfríkà: Orisun itumo oro, Itan, Awon agbegbe  Namibia 825,418 2,108,665 2.6 Windhoek
Áfríkà: Orisun itumo oro, Itan, Awon agbegbe  South Africa 1,219,912 49,052,489 40.2 Bloemfontein, Cape Town, Pretoria
Áfríkà: Orisun itumo oro, Itan, Awon agbegbe  Swaziland 17,363 1,123,913 64.7 Mbabane
Western Africa: 6,144,013 296,186,492 48.2
Áfríkà: Orisun itumo oro, Itan, Awon agbegbe  Benin 112,620 8,791,832 78.0 Porto-Novo
Áfríkà: Orisun itumo oro, Itan, Awon agbegbe 
Burkina Faso 
274,200 15,746,232 57.4 Ouagadougou
Áfríkà: Orisun itumo oro, Itan, Awon agbegbe  Cape Verde 4,033 429,474 107.3 Praia
Áfríkà: Orisun itumo oro, Itan, Awon agbegbe  Côte d'Ivoire 322,460 20,617,068 63.9 Abidjan, Yamoussoukro
Áfríkà: Orisun itumo oro, Itan, Awon agbegbe 
Gambia 
11,300 1,782,893 157.7 Banjul
Áfríkà: Orisun itumo oro, Itan, Awon agbegbe  Ghana 239,460 23,832,495 99.5 Accra
Áfríkà: Orisun itumo oro, Itan, Awon agbegbe  Guinea 245,857 10,057,975 40.9 Conakry
Áfríkà: Orisun itumo oro, Itan, Awon agbegbe  Guinea-Bissau 36,120 1,533,964 42.5 Bissau
Áfríkà: Orisun itumo oro, Itan, Awon agbegbe  Liberia 111,370 3,441,790 30.9 Monrovia
Áfríkà: Orisun itumo oro, Itan, Awon agbegbe  Mali 1,240,000 12,666,987 10.2 Bamako
Áfríkà: Orisun itumo oro, Itan, Awon agbegbe 
Mauritania 
1,030,700 3,129,486 3.0 Nouakchott
Áfríkà: Orisun itumo oro, Itan, Awon agbegbe  Niger 1,267,000 15,306,252 12.1 Niamey
Áfríkà: Orisun itumo oro, Itan, Awon agbegbe  Nigeria 923,768 149,229,090 161.5 Abuja
Áfríkà: Orisun itumo oro, Itan, Awon agbegbe  Saint Helena, Ascension and Tristan da Cunha (UK) 410 7,637 14.4 Jamestown
Áfríkà: Orisun itumo oro, Itan, Awon agbegbe  Senegal 196,190 13,711,597 69.9 Dakar
Áfríkà: Orisun itumo oro, Itan, Awon agbegbe  Sierra Leone 71,740 6,440,053 89.9 Freetown
Áfríkà: Orisun itumo oro, Itan, Awon agbegbe  Togo 56,785 6,019,877 106.0 Lomé
Africa Total 30,368,609 1,001,320,281 33.0




Itokasi

Tags:

Áfríkà Orisun itumo oroÁfríkà ItanÁfríkà Awon agbegbeÁfríkà ItokasiÁfríkàAfrican UnionAsia (orile)Atlantic OceanContinentEarthHumanIndian OceanMadagascarMediterranean SeaMoroccoRed SeaSahrawi Arab Democratic RepublicSinai PeninsulaSquare mileSuez CanalWorld

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Ere idarayaRodrigo Borja CevallosJoe BidenFósfórùSixto Durán BallénIlẹ̀ YorùbáẸ̀wádún 2010EwìAtlantaÌdíje Wimbledon 1979 − Àwọn Obìnrin ẸnìkanÀmì ọ̀pá àṣẹ ilẹ̀ Ẹ́gíptìRobert S. MullikenCorine OnyangoṢE (Idanilaraya)Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́KentuckyẸ̀sìn IslamOlógbòMọ́rísìAlbert Szent-GyörgyiKárbọ̀nù12766 PaschenÀmì ọ̀pá àṣẹ ilẹ̀ Côte d'IvoireMpumalangaMenachem BeginAndrew JacksonISO 3166-1Mamerto UrriolagoitiaSanusi Lamido SanusiLahoreMose BìlísìIyipada oju-ọjọ ni South AfricaOkey BakassiChaudhry Shujaat Hussain10 AugustÌránìAlbrecht KosselL.uy.bbEmilio EstradaSigourney WeaverÀsìá ilẹ̀ Bárbádọ̀s3703 VolkonskayaMargaret ThatcherLoquatMonicazationNnamdi AzikiweṢàngóOrílẹ̀ èdè AmericaMandy Patinkin4 (nọ́mbà)Mandraka DamÀrokòIṣẹ́ Àgbẹ̀Ògún LákáayéEhoroUrho KekkonenISO 4217Carl Linnaeus2 DecemberEsther Oluremi ObasanjoPorto-NovoR. Lee Ermey🡆 More