Jacob Zuma jẹ́ ààrẹ orílẹ̀ èdè Gúúsù Áfíríkà tẹ́lẹ́.
Ó wolé ní osù kejìlá odún 2006 gégé bí alága fún egbé African National Congress (ANC) ní Guusu Afrika. Olóyè ni ó jé ní àárín àwọn Zulu. Ní ọjọ́ karùn-ún osù kìíní odún 2007, ó fé Nompumeledo Ntuli, ọmọ ọdún mẹ́tàlélọ́gbọ̀n gẹ́gẹ́ bí ìyàwó rẹ̀ karin lẹ́yìn ìgbà tí ó ti bí ọmọ méjì fún un. 1943 ni wọ́n bí Jacob Zuma. Ìyàwó rẹ̀ kan tí orúkọ rẹ̀ ní jẹ́ Kate pa ara rẹ̀ ní ọdúin 2000 nítorí pé ó ní ìgbéyàwó tí àwọn ti ṣe fún ọfún mẹ́rìnlélógún kò rọgbọ. Ọmọ ọdún mẹ́rìnlélógójì ni Kate nígbà náà: Ní ọdún 2005 ni President thabo Mbaki yọ Zuma kúrò ní ipò igbákejì àrẹ nítorí ìwà ìbàjẹ́. Ní ọdún 2006 ni wón fi ẹ̀sùn kan Zuma pé ó fi ipá bá obìnrin kan tí ó ní HIV lo pò. Kò jẹ̀bi ẹ̀sùn náà. Ni Oṣu Kẹsan ọdun 2021, idajọ ododo jẹrisi idalẹjọ ti Jacob Zuma si oṣu mẹẹdogun ninu tubu.
His Excellency Jacob Zuma | |
---|---|
President of South Africa | |
In office 9 May 2009 – 14 February 2018 | |
Deputy | Kgalema Motlanthe Cyril Ramaphosa |
Asíwájú | Kgalema Motlanthe |
Arọ́pò | Cyril Ramaphosa |
President of the African National Congress | |
In office 18 December 2007 – 18 December 2017 | |
Deputy | Kgalema Motlanthe Cyril Ramaphosa |
Asíwájú | Thabo Mbeki |
Arọ́pò | Cyril Ramaphosa |
Member of Parliament | |
In office 1999–2005 | |
Deputy President of South Africa | |
In office 14 June 1999 – 14 June 2005 | |
Ààrẹ | Thabo Mbeki |
Asíwájú | Thabo Mbeki |
Arọ́pò | Phumzile Mlambo-Ngcuka |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Jacob Gedleyihlekisa Zuma 12 Oṣù Kẹrin 1942 Inkandla, South Africa |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | African National Congress (1959–present) |
Other political affiliations | Communist Party (1963–present) |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Gertrude Sizakele Khumalo (1973–present) Kate Zuma (1976–2000) Nkosazana Dlamini (1982–1998) Nompumelelo Ntuli (2008 – present) |
Àwọn ọmọ | 20 |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Jacob Zuma, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.