Ilẹ̀ ọbalúayé Brítánìì (The British Empire) je awon itedo, amusin, protektoreti, ile agbefun, ati awon other agbegbe miran baun ti won je jijobale tabi mimojuto latowo orile-ede Britani, ti won bere pelu awon amusin okere ati ibujoko itaja that had originated with the overseas colonies and ibujoko itaja ti won je didasile latowo Ilegeesi ni opin orundun 16th ati ibere orundun 17th.
O je ile obaluaye totobijulo ninu itan aye ati, fun igba to ju orundun kan lo, o je eyi to lagbarajulo laye. Nigba tio fi di odun 1922, Ile Obaluaye Britani joba lori awon eniyan to to legbegberun bi 458 eniyan, eyi to je ida kan ninu merin iye awon eniyan aye nigbana, o si ni ile to toju 12,000,000 square miles (31,080,000 km2) lo: eyun ida kan ninu merin gbogbo ile Aye.
British Empire | |
---|---|
Àsìá | |
Awon ile agbaye, ti o fi igbakan je ara Ile Obaluaye Britanii. Current British overseas territories are underlined in red. |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Ilẹ̀ ọbalúayé Brítánìì, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.